Jesu Olore Medley (Part 1)

Jesu Oloore o (Oh Oloore)
Messiah Oloore o (Oh Oloore)
O ku nitori mi o (Oh Oloore)
O jiya nitori mi (Oh Oloore)
Jesu Oloore o (Oh Oloore)
Baba Oloore o (Oh Oloore)
E wa ba mi gbo 'royin rere (Iroyin ayo iroyin rere)
Iroyin to ju 'royin lo ni ti Jesu o (Iroyin ayo iroyin rere)
P'eni to f'emi re lele (Iroyin ayo iroyin rere)
Jesu to f'emi re lele (Iroyin ayo iroyin rere)
O ku nitori ese omo araye o (Iroyin ayo iroyin rere)
Iroyin to ju 'royin lo ni ti Jesu o (Iroyin ayo iroyin rere)
P'enikan f'emi re lele (Iroyin ayo iroyin rere)
O ku nitori ese omo araye o (Iroyin ayo iroyin rere)
Jesu Oloore o (Oh Oloore)
Baba Oloore o (Oh Oloore)
O ku nitori mi o (Oh Oloore)
O tun jiya nitori mi (Oh Oloore)
Jesu Oloore o (Oh Oloore)
Messiah Oloore o (Oh Oloore)
O ku nitori mi o (Oh Oloore)
O tun jiya nitori re (Oh Oloore)
E wa ba mi gbo 'royin rere (Iroyin ayo iroyin rere)
Iroyin to ju 'royin lo ni ti Jesu o (Iroyin ayo iroyin rere)
P'enikan f'emi re lele (Iroyin ayo iroyin rere)
O ku nitori ese omo araye o (Iroyin ayo iroyin rere)
Iroyin to ju 'royin lo ni ti Jesu o (Iroyin ayo iroyin rere)
P'enikan f'emi re lele (Iroyin ayo iroyin rere)
Wa elese, wa fun 'dariji
Eni kan n be to, to f'emi re lele
O ku nitori mi, O gba mi la
Jesu t'O ku nitori mi, O gba mi la
Messiah t'O ku nitori mi, O gba mi la
Ah O ku nitori mi, O gba mi la
Messiah t'O ku nitori mi, O gba mi la
Ah O ku nitori mi, O gba mi la
O ku nitori mi, O gba mi la
Messiah t'O ku nitori mi, O gba mi la
Wa elese, wa fun 'dariji
Eni kan n be to, to f'emi re lele
O ku nitori mi, O gba mi la
Jesu t'O ku nitori mi, O gba mi la
Messiah t'O ku nitori mi, O gba mi la
Ah O ku nitori mi, O gba mi la
Jesu t'O ku nitori mi, O gba mi la
Messiah t'O ku nitori mi, O gba mi la
Jesu t'O ku nitori mi, O gba mi la
Messiah t'O ku nitori mi, O gba mi la



Credits
Writer(s): Ebenezer Olasupo Obey-fabiyi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link