Eyin Ewe Iwoyi

Mo'de, mo'de, mo'de, mo'de, mo'de, mo'de
Moni,mo'de, mo'de, mo'de, mo'de, mo'de
Olu'aye fuji o, ara ba n bi
Igbeyin l'alayo npao, oro mi doni'gbeyin o

Ami gunyan ninu odo, kasebe ninu epo epa eni ma yo a yo
Igbeyin l'alayo npao, oro mi doni'gbeyin o
Eyin Ewe iwo yi, eyin ti r'orisirisi
Airin jina lai rabuke okere
Airin jina lai rabuke okere
Taba ri titi ari to n fodo ibile jehun

Taba ri titi ari to n fodo ibile jehun,



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link