Igbekele Mi Medley

Mo ti fi Oluwa se'gbekele mi
Igbekele Oluwa kii ye o rara rara
Mo ti fi Oluwa se'gbekele mi
Igbekele Oluwa kii ye o rara rara

Mo ti f'Oluwa se'gbekele mi
Ta lo gb'oju le? Jesu ni mo gb'oju le
Atof'ara ti bi oke, ni mo gb'oju le
Ta lo gb'oju le? Jesu ni mo gb'oju le
Igbekele Oluwa kii ye o rara rara

Mo ti fi Oluwa se'gbekele mi
Igbekele Oluwa kii ye o rara rara

Mo gb'okan le Baba l'oke, Mo gb'okan le
Ta lo gb'oju le? Jesu ni mo gb'oju le
Atof'ara ti bi oke, ni mo gb'oju le
Igbekele Oluwa kii ye o rara rara

Mo ti fi Oluwa se'gbekele mi
Igbekele Oluwa kii ye o rara rara

Ma hu'wa ese
Tete gbo ti Jesu l'oni
Ma hu'wa ese
Tete gbo ti Jesu l'oni
Ma hu'wa ese
Tete gbo ti Jesu l'oni
Ma hu'wa ese
Tete gbo ti Jesu l'oni

Dakun ye o (ye o)
Dakun ye o
Dakun ma hu'wa ese
Tete gbo ti, Jesu l'oni
Dakun ye o (ye o)
Dakun ye o
Dakun ma hu'wa ese
Tete gbo ti, Jesu l'oni

Jesu f'eje re ru'bo, Fun ese t'emi
Jesu f'eje re ru'bo, Fun ese t'ire
Se ru'bo f'ese mi, Se ru'bo f'ese re
Se ru'bo f'ese mi, Se ru'bo f'ese re o
Patapata

Ma ta'pa s'Olorun o
Ma sa'igboran s'Olorun o
Igboran san ju ebo lo
Ma ta'pa s'Olorun o
Ma ta'pa s'Olorun o
Ma sa'igboran s'Olorun o
Igboran san ju ebo lo o
Ma ta'pa s'Olorun o

Jesu f'eje re ru'bo, Fun ese t'emi
Jesu f'eje re ru'bo, Fun ese t'ire
Se ru'bo f'ese mi, Se ru'bo f'ese re
Se ru'bo f'ese mi, Se ru'bo f'ese re o
Patapata

O so gbogbo re ni calvary, O f'eje re ru'bo
O wipeee, o pari, o pari
Jesu f'eje we mi o, o pari

Ibanuje ti tan, idamu aye pari
O pari, o pari
Jesu f'eje we mi o, o pari
Ail'owo ti tan, air'omo bi pari (o pari)
O pari, o pari
Jesu f'eje we mi o, o pari
Isoro aye ti tan, ain'ise lowo pari (o pari)
O pari, o pari
Jesu f'eje we mi o, o pari

Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yoo t'oke wa
Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yoo t'oke wa
Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yoo t'oke wa

Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yooo t'ooooke wa
Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yoo t'oke wa

Iranl'owo baba, Iranl'owo omo
Iranl'owo emi mimo l'at'oke wa
Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yoo t'oke wa

Iranl'owo baba, Iranl'owo omo
Iranl'owo emi mimo l'at'oooke wa
Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yoo t'oke wa
Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yoo t'oke wa

Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yooo t'ooooke wa
Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yoo t'oke wa
Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yoo t'oke wa
Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yoo t'oke wa
Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo mi yoo t'oke wa

Iranl'owo baba, Iranl'owo omo
Iranl'owo emi mimo l'at'oke wa
Mo gb'oju mi s'oke, s'ori oke wonni
Iranl'owo miiiiiii



Credits
Writer(s): Ebenezer Olasupo Obey-fabiyi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link