Lambebe
Heaven shine the light on me
Heaven shine the light on me
I buy car for my mummy
I buy car for her na ni
Tẹ ba gbọ pe mo wa kọ'le
Ẹ ma binu yẹn ṣá no ni
We be balling every day
Every day noni o
Lambebe o gbọdọ wọ́n ni ile alata (ni ile alata)
Owo o gbọdọ wọ́n ninu ile wa (ninu ile t'awa)
Oriburuku o gbọdọ ṣá, I see you later (see you later)
Koni buru fun mi, mi o ni ṣe trade by barter (laye ti mo wa)

Koni buru fun mi, mi o ni ṣe trade by barter
Mo ma wa okay
Tẹ bari, ta gb'ọtí wa soke
Si àwọn ọmọge, káwọn wọn sókè
O yẹ kẹ ti mọ p'ati okay (ati okay)
Walai-talai, mo w'owo lọ lànà, mogbayi
Mo sare gbowo mi, mó gbayì
Èṣù fẹ tempt mi, o má ṣe, Èṣù lo gọ bayi
Eh-hey, eleyi, o gidi gan o (gidi gan)
They asking, "Na who the boy o?" (The boy)
Whether na home or away, I dey rep my city
'Til you're the-the boy o
Apoti tawa fi ń jókòó, ṣ'o nù làwọn gun lẹbọ
Ìyẹn ko kan mi, them dey yan dust, ẹnu lẹbọ
Heaven shine the light on me
Heaven shine the light on me
I buy car for my mummy
I buy car for her na ni
Tẹ ba gbọ pe mo wa kọ'le
Ẹ ma binu yẹn ṣá no ni
We be balling every day
Every day noni o
Lambebe o gbọdọ wọ́n ile alata (ni ile alata)
Owo o gbọdọ wọ́n ile wa (ninu ile t'awa)

Oriburuku o gbọdọ ṣá, I see you later (see you later) (God forbid)

Ah, ki lo ń jẹ Ajinomoto?
Mo gb'ero ṣábagọ sinu mọto
Mo tun gẹ fila bi ẹni jẹ lotto (ye!)
Àwọn ọmọge boyin, wọn ya photo, wọn ya photo
Ki ń to mọ what's up, Bọlá ti sa picture s'ori Instagram
Instagram Bọla dey show location
Àwọn ẹrúkú tun yapa s'occasion o, yapa s'occasion

Apoti tawa fi ń jókòó, ṣ'o nù làwọn gun lẹ'bọ

Ẹnu lẹ'bọ o-, ẹnu lẹbọ
Them dey yan dust, ẹnu lẹbọ

Credits
Writer(s): Archibong U Michael, Olamide Adedeji
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.