Oro Oluwa
Ọrọ' Olúwa kòni lọ láì ṣẹ'
Ìfẹ' Olúwa kòní lọ láì ṣẹ'
Ìmọ' Olúwa kòni lọ láì ṣẹ'
Òun mo rí yẹ kó ba mí lẹ'ru
Òun mo rí yẹ kó mì mí lọ'kàn
Oti lẹ' yẹ kó fò mí láyà
Ṣùgbọ'n mo pinnu láti dí imú Ọlọrun òdòdó ni
Sii bẹ mo pinnu láti mọ kan ro t'ori mo mọ pé Ọ'rọ' Olúwa, kò ní lọ láì ṣẹ'
Ìfẹ' Olúwa kó ni lọ láì ṣẹ'
Ìmọ' Olúwa kòni lọ láì ṣẹ'
Kò ní lọ láì ṣẹ'
Kò ní lọ láì ṣẹ'
Ìgbàgbọ' rẹ lo ń béèrè
Ìlérí a má ṣẹ'
Hmmmmm...
Ìbànújẹ' lè wá síbẹ' ọ'rọ' rẹ á ṣẹ'
Ìkorò lè pọ' o ṣùgb 'adun la ja si
Mo gbójú mí ṣá pá òkè
Iranwọ' mí n bẹ láti ọ'dọ' Ọlọ'run òdòdó
Ìdánilójú yí mú 'retí wá t'ori mó mọ pé
Ọ'rọ' rẹ sì mí (hmmm) kò ní lọ láì ṣẹ'
Ìfẹ' rẹ' sí mí réré ni kò ní lọ láì ṣẹ'
Ìmọ' Olúwa kó ni lọ láì ṣẹ'
Ọlọ'run kìí ṣ' ènìyàn tó máa ṣe ké
Oti wí bẹ' àṣẹ bẹ dandan lo jẹ'
Bó tilẹ' wù kó rí ọ'rọ' rẹ àṣẹ
Olè pẹ' díẹ' ṣùgbọ́n pé kò yẹ (hmmm) rárá rárá
Òfìfo á dọ" pọ ìrora á di' rọrùn ká ní 'retí
Adùn aapọ' aapẹ'
A fi rí gidi a fẹ'rẹ'ẹ' gẹ'dẹ' àpẹẹ
Ìgbàgbọ' rẹ kò má mi sẹ ìlérí àṣẹ
Ìgbàgbọ' rẹ kò má mi sẹ ìlérí a má ṣẹ
Ìgbàgbọ' rẹ kò má mi ṣẹ ìlérí àṣẹ
Òun órí lè má ba ọ' lẹ'ru
Òun órí lè má mi ọ lọ'kàn
Oti lẹ' yẹ kó fò ọ láyà
Ṣùgbọ'n ko pinnu láti dí imú Ọlọrun òdòdó ni
Sii bẹ pinnu láti mọ kan ro t'ori àjọ mọ ní pé
Ọ'rọ' rẹ sì wá réré ní (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Ìfẹ' Olúwa sì wá réré ni (Kó ni lọ láì ṣẹ')
O kan jọ búburú ni koni burú fún ọ ọmọ ènìyàn ọ'rọ' rẹ kii yẹ (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Mójú kúrò nínú Júù Júù tó yọ ká gbójú rẹ sókè iranwo àwa (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Òun ni lọ'wọ' lọ'wọ' iranlọwọ nígbà tó wà àti 'gbá tí ó wà ọ'rọ' rẹ kò ní lọ láì ṣẹ' (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Gba lolu gbá lolu tọ gbá l' olùkọ' at' olùdarí ọ'rọ' rẹ réré ni (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Eh! Ọ'rọ' Olúwa (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Níwọ'n ìgbà tí mo gbẹ' kẹ'l 'olú èmi ó ní rí' tijú kan lai lai lai (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Mo gbà lólu 'rán lọ'wọ' mi ò mọ l' àrán mi lọ'wọ' ọ'rọ' rẹ kò ní láì ṣẹ' (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Oti wí bẹ'ẹ' àṣẹ bẹ'ẹ' fún mi mo dúró mo dúró (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Eh! Eh! Eh! Ọ'rọ' Olúwa o (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Koni lọ láì ṣẹ' kò ní lọ láì ṣẹ' gbà bẹ gba bẹ (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Eh! Eh! Eh! Ọ'rọ' rẹ siwa ó rere ní (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Tújú rẹ ká tújú rẹ ká ọ'rọ' rẹ kò ní lọ láì ṣẹ' (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Lábẹ' bó tilẹ' wù kori ọ'rọ' rẹ kọ'ni lọ láìṣe gbà bẹ (Kò ní lọ láì ṣẹ')
Hmm... Ọ'rọ' Olúwa ó (Kò ní lọ láì ṣẹ')

Credits
Writer(s): Sola Allyson, Tunji Dada
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2025 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.