Ero Oja
Ero oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo
Ero oja olomo
Ja lo lo, ja lo lo
Ero oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo
Ero oja olomo
Ja lo lo, ja lo lo
Ki le ti s'oja yi si o?
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti s'aye si?
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti s'oja yi naa?
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
A bebe, e ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
E w'oja yi se, e ba wa se k'o da
Ja lo lo ja lo lo
E w'oja yi se, e ba wa se k'o da
Ja lo lo ja lo lo
A ki yin ooo, eyin agba
E ku agba eyin agba to t'agba to t'aye se, agba yin a dale
Omode ni mi oooo, k'Oluwa da mi lagba
Agba to n mu'le ro
To to se bi imoran, mi o to gba yin ni 'moran
Ise Olorun ni mo n je
Ki le ti s'aye si o, eyin to di 'po mu
Ki le ti lo'po si, eyin ta gb' ola fun
A sipe e ba wa s'oja yi ko ma la tu mo wa lori
A sipe e ba wa w'oja yi naa ko ma la tu mo wa lori o
Eyi te ba se la maa ba o aanu ola wa, e je o se yin
Ero oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo
Ero oja olomo
Ja lo lo, ja lo lo
Eyin agba t'o wa lori ile, ero oja
Ja lo lo, ja lo lo
Eyin agba t'o wa niwaju, eyin lero oja
Ja lo lo, ja lo lo
Ki le ti s'oja yi si o?
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti s'aye si?
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti s'oja yi naa?
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
To to se bi imoran, mi o to gba yin ni 'moran
Ja lo lo ja lo lo
E w'oja yi na o, e ba wa se k'o da
Ja lo lo ja lo lo
Nitori ola wa, e ba wa se k'o da
Ja lo lo ja lo lo
Ipokipo t'a ba wa, k'a ranti Eni to lemi to fun wa mi
B'agba miran ba soro, a b'omi tutu s'okan mi
E je a maa ranti Oba orun to f'ola ran wa ni 'se s'aye
E wo awon omo to wa loke ohun bi won ti n p'ebi mo 'nu
E wo awon eni to wa lapa ibi bi won ti n rare k'aye
Ranti Eni to lemi re, ranti Eni nla to le ji, to le pa ni iseju kan
O ki 'yun bo 'le, o fa 'yun yo
Won ke 'borun meje, won gbe 'gba ata
Isoro si re, ihuwasi re, ilo 'po si re, eh eh
Ranti Oba to lesan o
Ero oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo
Eyin obi wa, eyin egbon wa to wa niwaju
Ja lo lo, ja lo lo
Ki le ti s'oja yi si o?
Ja lo lo ja lo lo
Obiri laye o, ko duro sodo enikan
Ja lo lo ja lo lo
Eyi to ba se la o royin ranti ola
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti s'aye si o?
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti na 'ja yi si?
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori o o
Ja lo lo ja lo lo
E w'oja yi na o, e ba wa se k'o da
Ja lo lo ja lo lo
Nitori ola wa, a bebe, e ba wa se k'o da
Ja lo lo ja lo lo
Ebe la be o
Nile loko lodo eyin agba e w' oja yi na
Ko ma baje la n toro
Agbara atorun wa a di yin mu o
Eleduwa a gba fun wa,
Amin o
Amin ase
Ero oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo
E gb' ekun wa ba se n bebe eyin ero oja
Ja lo lo, ja lo lo
B'aye ti ri yi o da, eyin ero oja
Ja lo lo, ja lo lo
Ife eleda fun wa ko ni 'yi o rara
Ja lo lo, ja lo lo
Nitori ola wa, e w' ekun wa
Ja lo lo ja lo lo
B'aye ti ri yi o da o
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti s'oja yi na?
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
Ja lo lo, ja lo lo
Ero oja olomo
Ja lo lo, ja lo lo
Ero oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo
Ero oja olomo
Ja lo lo, ja lo lo
Ki le ti s'oja yi si o?
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti s'aye si?
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti s'oja yi naa?
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
A bebe, e ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
E w'oja yi se, e ba wa se k'o da
Ja lo lo ja lo lo
E w'oja yi se, e ba wa se k'o da
Ja lo lo ja lo lo
A ki yin ooo, eyin agba
E ku agba eyin agba to t'agba to t'aye se, agba yin a dale
Omode ni mi oooo, k'Oluwa da mi lagba
Agba to n mu'le ro
To to se bi imoran, mi o to gba yin ni 'moran
Ise Olorun ni mo n je
Ki le ti s'aye si o, eyin to di 'po mu
Ki le ti lo'po si, eyin ta gb' ola fun
A sipe e ba wa s'oja yi ko ma la tu mo wa lori
A sipe e ba wa w'oja yi naa ko ma la tu mo wa lori o
Eyi te ba se la maa ba o aanu ola wa, e je o se yin
Ero oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo
Ero oja olomo
Ja lo lo, ja lo lo
Eyin agba t'o wa lori ile, ero oja
Ja lo lo, ja lo lo
Eyin agba t'o wa niwaju, eyin lero oja
Ja lo lo, ja lo lo
Ki le ti s'oja yi si o?
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti s'aye si?
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti s'oja yi naa?
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
To to se bi imoran, mi o to gba yin ni 'moran
Ja lo lo ja lo lo
E w'oja yi na o, e ba wa se k'o da
Ja lo lo ja lo lo
Nitori ola wa, e ba wa se k'o da
Ja lo lo ja lo lo
Ipokipo t'a ba wa, k'a ranti Eni to lemi to fun wa mi
B'agba miran ba soro, a b'omi tutu s'okan mi
E je a maa ranti Oba orun to f'ola ran wa ni 'se s'aye
E wo awon omo to wa loke ohun bi won ti n p'ebi mo 'nu
E wo awon eni to wa lapa ibi bi won ti n rare k'aye
Ranti Eni to lemi re, ranti Eni nla to le ji, to le pa ni iseju kan
O ki 'yun bo 'le, o fa 'yun yo
Won ke 'borun meje, won gbe 'gba ata
Isoro si re, ihuwasi re, ilo 'po si re, eh eh
Ranti Oba to lesan o
Ero oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo
Eyin obi wa, eyin egbon wa to wa niwaju
Ja lo lo, ja lo lo
Ki le ti s'oja yi si o?
Ja lo lo ja lo lo
Obiri laye o, ko duro sodo enikan
Ja lo lo ja lo lo
Eyi to ba se la o royin ranti ola
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti s'aye si o?
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti na 'ja yi si?
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori o o
Ja lo lo ja lo lo
E w'oja yi na o, e ba wa se k'o da
Ja lo lo ja lo lo
Nitori ola wa, a bebe, e ba wa se k'o da
Ja lo lo ja lo lo
Ebe la be o
Nile loko lodo eyin agba e w' oja yi na
Ko ma baje la n toro
Agbara atorun wa a di yin mu o
Eleduwa a gba fun wa,
Amin o
Amin ase
Ero oja olowo
Ja lo lo, ja lo lo
E gb' ekun wa ba se n bebe eyin ero oja
Ja lo lo, ja lo lo
B'aye ti ri yi o da, eyin ero oja
Ja lo lo, ja lo lo
Ife eleda fun wa ko ni 'yi o rara
Ja lo lo, ja lo lo
Nitori ola wa, e w' ekun wa
Ja lo lo ja lo lo
B'aye ti ri yi o da o
Ja lo lo ja lo lo
Ki le ti s'oja yi na?
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
E ma ma je k'oja yi tu mo wa lori
Ja lo lo ja lo lo
Credits
Writer(s): Sola Allyson
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2025 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.