Rababa (Medley 4)

This is how we ra Bàbá
Ra bàbà, Ra bàbà
And this is how we komole
This is how we ra Bàbá fún bàbá
And this is how we komole
This is how we ra bàbà fún bàbá
And this is how we komole
This is how we ra bàbà fún Jésù o
And this is how we komole o

Kilo mú Tomiwa
Ohun réré lómú Tomiwa

...

Emi leni t'aiye ti ro
Wọni ko le da ohun ore ṣe
Sugbon mo ri anu rẹ gba
Olu òrun loba mi
Iwo nkọ
Emi leni t'aiye ti ro
Wọni ko le da ohun ore ṣe
Sugbon mo ri anu rẹ gba
Olu òrun loba mi ṣe

Ọba lori aiye
We worship you Jehovah
Ọba lori aiye ati orun
Ọba lori aiye
Ọba lori aiye ati orun
Mo wa júbà rè o
Akoda aiye, asèdá orun
Oke lẹyìn onigbagbo
Wa ba mi ṣe
Oke lẹyìn onigbagbo
Wa ba mi ṣe
Oke lẹyìn onigbagbo
Wa ba mi ṣe
Oke lẹyìn onigbagbo
Wa ba mi ṣe

Ọba to to to to to to to kari aiye
Emi ni, emi ni, emi ni máṣe beru
Eba mi gbe oruko re
Emi ni tin je emini, oloruko nla
Emi ni máṣe beru
Eba mi gbe oruko re
Emi ni tin je emini, oloruko nla
Emi ni máṣe beru
Oloruko nla la la la la la la la la la
Oyigiyigi yigi yigi kabiyesi
Ọba to to to to kari ayé
Emi ni, emi ni, emi ni
Máṣe bẹru

Kabiyesi o, ese o



Credits
Writer(s): Lara George
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link