Je 'Le O Sinmi

Ní kékeré, a má ńṣeré
À mà ń f'àwọn àgbààgbà ṣeré
À má ńmere
Ìyá Dele, sọ fún Dele
Kò ye fó 'na, kò tó wo 'na, ko to mere

Bọ 'mọdé ńṣeré, kò tó ṣeré délé
Àwọn àgbà-gbà wọn mà ṣé'to were-were
Bọ 'mọdé ńṣíṣẹ, ko tó rí jẹ
Ìtìjú ní fún àwọn àgbà-gbà to rán ní ṣẹ

Jẹ lé o sinmi ooo
Jẹ lé o sinmi
Jẹ k'ọmọdé o kàwé
Kò kẹ'kọ' jèrè
Jẹ lé o sinmi ooo
Jẹ lé o sinmi
Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were

A mà ń ṣeré
À mà ń sáré
À mà ńṣubú, à mà ń dídé, a mà ńdele
Ìyá Taye sọ fún Taye
Kò yé sọrọ, kò to mọ'rọ yeke-yeke

K'ọmọ o to sa ńlé
Ko tó dí pé o ń sáré kírì
Àwọn àgbà-gbà wọn má ṣètò were-were
B'ọmọdé ń ṣíṣẹ, ah, ko to rí jẹ
Ìtìjú ní fún àwọn àgbà-gbà to rán ní ṣẹ

Jẹ lé o sinmi ooo
Jẹ lé o sinmi
Jẹ k'ọmọdé o kàwé
Kò kẹ'kọ' jèrè
Jẹ lé o sinmi o, o sinmi
Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were (were-were)

Wure, wure, wure e-

Jẹ lé o sinmi (jẹ lé o sinmi)
Ko sinmi (ko sinmi)
K'ọmọdé o kàwé (k'ọmọdé o kàwé)
Kò jèrè (kò jèrè)
Jẹ lé o sinmi o (jẹ lé o sinmi o)
Ko sinmi (ko sinmi)
Àwọn àgbà-gbà múra sí ṣẹ were-were

Ko sinmi (ko sinmi)
Ani, ko sinmi (ani, ko sinmi)
Ko kà'we (ko kà'we)
Ko jèrè (ko jèrè)
Jẹ lé o sinmi o (jẹ lé o sinmi o)
Ko sinmi (ko sinmi)
Ko, ko sinmi, ko-ko jèrè



Credits
Writer(s): Ashimi Ibrahim
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link