Oshodi Oke

Omode yi f'efe sile, ko je a m'ere se
Emi re la d'owo po, emi won ko
Emi re la d'owo po, emi won ko
Eruku oshodi oke, to n mi jigi-jigi
E le won la mi ji-ji-ji-mi, to n mi jolo-jolo
Ma wo ariwo oja, ma wo ariwo oja
Sidi mere han fun ebi won, e-i-u
A o jo logba yi pe ni
Olubunmi Wasiu, original landcruiser

Omode yi f'efe sile, ko je a m'ere se
Emi re la d'owo po, emi won ko
Emi re la de 'sale, emi won ko
Eruku oshodi oke, to n mi jigi-jigi
E le won la mi ji-ji-, to n mi jolo-jolo
Ma wo ariwo oja, ma wo ariwo oja
Sidi mere han fun ebi won, e-i-u
A o jo logba yi pe ni
Olubunmi Wasiu, original landcruiser
Omode yi o le pami l'ayo, bosi gbangba ka jo

Ma f'owo kan be yen, ijo ni o bami jo ooo, Fabiyi
Ma f'owo kan be yen, ijo ni o bami jo ooo, Fabiyi



Credits
Writer(s): King Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link