Halleluyah (feat. Oniyo)

Ile ayo, ile ogo
mumi de be, Baba mi.
Ile ayo, ile ogo
Mumi de be, Baba mi.
Awon Angeli orun,
Wo n ke halleluyah s'ologo
Mo fe darapo mo won o
Ki n le ma juba ogo re
Awon Angeli orun,
Won ke halleluyah s'olorun
Mo fe darapo mo won o o o
Ki n le ma juba ogo re

Ma ke halleluyah, halleluyah, halleluyah, s'olorun
Halleluyah, halleluyah, halleluyah, s'ologo
Halleluyah, halleluyah, halleluyah, s'olorun

Ile ayo, ile ogo
mumi de be, Baba mi.
Ile ayo, ile ogo
mumi de be, Baba mi.
Ile ayo, ile ogo
mumi de be, Baba mi

Awon Angeli orun,
Wo n ke halleluyah s'ologo
Mo fe darapo mo won
Ki n le ma juba s'ologo
Awon Angeli orun,
Wo n ke halleluyah s'ologo
Mo fe darapo mo won
Ki n le ma juba ogo re
Ki n wa ma ko

Halleluyah (halleluyah),
Halleluyah (halleluyah)
Halleluyah (halleluyah) si Baba
Halleluyah (hallelujah)
Halleluyah (halleluyah)
Halleluyah (halleluyah) s'ologo
Halle-halleluyah, halleluyah, halleluyah so baba
Ma ke halleluyah, halleluyah s'olorun
Halleluyah, Halleluyah s'olorun
Halleluyah, Halleluyah, Halleluyah-ah-ah halleluyah
Ile ayo, ile ogo
Mumi de be, Baba mi



Credits
Writer(s): Mobolaji Dekunle-oniyo
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link