Oré

Má yà'lé mi, ìwọ ọrẹ àt'ojúbọ onílé
Má yà'lé mi, ìwọ ọrẹ agb'ọkọ l'ọkọ
Má yà'lé mi, ìwọ ọrẹ àdúgbò
Má yà'lé mi, má yà'lé k'ọmọ

Ọrẹ tí mo mú bí àbúrò
Ọrẹ, orẹ tí mo ṣe dáradára
Ọrẹ tí mo f'inú hàn
Owá dà mí o, ó tú mi s'íta

Ah, o dà b'ọrọ àná
Eh, b'ọrọ àná

Don't come to my house, iwo ọrẹ èké àdúgbò
Don't come to my house, iwọ ọrẹ ada'lérú
Má yà'lé mi, ìwọ ọrẹ ko fẹni fẹ're
Má yà'lé mi o, má yà'lé rara

Iṣe ni mo lọ wá lọ'jọ yìí o
Ọkọ tó fẹ'mi s'ílé, kò kú lo wá'ṣe ṣe
Láwọn méjèèjì, wọn bẹrẹ' ìṣekúṣe
Wọn wù'wà ọmọdé
Wọn ṣe bó ṣe wùn wọn

Ah, o dà b'ọrọ àná
Eh, b'ọrọ àná

Eh, dà b'ọrọ àná
Oh, b'ọrọ àná

Ẹ wá wo ìjà l'ọjọ yẹn
Ẹ wá wo èrò tó tú'ta
Ẹ wá wo ẹjẹ n'ílẹ
Ah, ọrẹ, ọrẹ o, o tú mi s'íta

Ija ma dele mi
Má yà'lé mi, oh-oh-oh (ile, ile)
I don't wanna see you no more (ile, ma ya'le mi)
Má yà'lé mi, oh-oh (Ija, ija)
Tiẹ máà béèrè mi n'lé (Ija ma dele mi)
Ah, má yà'lé mi, oh-oh (ile, ile)
I don't wanna see you no more (ile, ma ya'le mi)
Ọrẹ, ìṣé bùṣe, k'ọwọ rẹ o-o (ija, ija, ija ma de'le mi)

Èmi ò ti ẹ lè pààyàn



Credits
Writer(s): Bukola Asa Elemide, Nicolas Wilhem Mollard, Benjamin Toshi Constant
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link