Kin Rere Je

Kín rí èrè jẹ labọ odé bí mo seń jáde lọ o
Mo ní mo bẹ ẹ Ọlọhun Ọba
(Kín rí èrè jẹ labọ odé)
Kín rí èrè jẹ labọ odé bí mo seń jáde lọ o
Mo ní mo bẹ ẹ Ọlọhun Ọba
(Kín rí èrè jẹ labọ odé)

Abi ohun gbogbo ní mèremère
Arambambi olówó yalúmọ'
Sàsà eyan ní fẹní lẹyìn bà o bá si nílé
Tẹrú tọmọ ní fẹní lójú ẹni
Ọmọ Alimọ Sadia mo gbé eré tá wí dé
K1 De Ultimate ẹ kì ọkọ on'jẹmila
Ayinde of majesty ó

Kín rí èrè jẹ labọ odé bí mo seń jáde lọ o
Ani mo bẹ ẹ Ọlọhun Ọba
(Kín rí èrè jẹ labọ odé)
Bí mo seń jáde lọ o
Mo ní mo bẹ ẹ Ọlọhun Ọba
(Kín rí èrè jẹ labọ odé)

Tá lo lẹfun?
Lekeleke lo lẹfun
Tá lo lóhùn?
Ológbùró lo lóhùn
Orin àti ìlù adídùn tí wa lóń se
Oluọmọ tí gbéré dé
Sebi ówu Allahu sati lo f'ojugun síwájú
Baba Idẹra Nimotallahi mí orin ńbẹ ìlù si wá ó

Dàndógó kọja ẹ'wù t'ọmọde le bínú dá
Dàndógó kọja ẹ'wù t'ọmọde le bínú dá
Dàndógó kọja ẹ'wù t'ọmọde le bínú dá
Dàndógó kọja ẹ'wù t'ọmọde le bínú dá
Kọmi la A B D ijó ọlọmọge to mo jó
Fi ibadi pòwe funmi ọmọge tó mọyì ìlù

Panboto riboto baby jẹ ka jọ jó
Panboto riboto baby jẹ ka jọ jó
Panboto riboto baby jẹ ka jọ jó
Panboto riboto baby jẹ ka jọ jó
Panboto riboto baby jẹ ka jọ jó

Ọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Ọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Alọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Ọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Irukẹrẹ mín yẹẹyẹ ó létí odò
Ọba fuji gbé eré de kajo kayọ
Irukẹrẹ mín yẹẹyẹ ó létí odò

Ọba fuji gbé eré de kajo kayọ
Ọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Alọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Bí mo seń kọ fuji mí emi lo ye o
Ko sẹni mọ pòn to dàbí ọlọmọ K1 De Ultimate
Torí Ọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Ọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Ọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ

Nítorí eré ní mofi ra asọ wálé
Nítorí íyì ni mofi ra ilẹkẹ ọrùn
Ẹyin o lesé kẹ má fẹsẹ ra ijó
Awa náà ó lesé ka má lulu fún yín ó
Torí pé ẹyin o lesé kẹ má fẹsẹ ra ijó
Awa náà ó lesé ka má lulu fún yín ó
Ẹyin ẹwo baby tón jó, tón jó tàpá tẹsẹ

Ẹyin ẹwo baby tón jó, tón jó tàpá tẹsẹ
Tí ilẹkẹ ńsọrọ
Ilẹkẹ ńsọrọ awọn bọbọ ranju
Bọbọ má ranju mọ ọlọmọge tí lọko

Ọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Ọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Mọ lo Ọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Ọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Ọba orin irú ọwá ìjọ nio bami jọ
Tán bání ta lo gbòde
Ayinde lo suyọ bí ọ'wàrà òjò ki ẹ sáré wa

Ki la fín mọ Ọba?
Adé là fín mọ Ọba
Ilẹkẹ ọrùn là fín mọ ìjòyè
Apó là fín mọ ọdẹ
T'ayinde bá dé tohùn tìlú
Ohún lẹ o fimọ wípé atunde

Kútúpà Kútúpà ẹsin dondo
Kútúpà Kútúpà ẹsin dondo
Kútúpà Kútúpà ẹsin dondo
Kútúpà Kútúpà ẹsin dondo

Eré fuji yìí ladun ó, oyin mọmọ
Kogbodo kan silẹ, ẹ f'asọ ko
Kútúpà Kútúpà ó ẹsin dondo
Kútúpà Kútúpà ẹsin dondo
Ẹlẹlẹ yí o lejù ó oyin mọmọ
Kogbodo kan silẹ, ẹ f'asọ ko
Ìdí àwẹnẹ yí gáju ó oyin mọmọ
Kogbodo kan silẹ, ẹ f'asọ ko



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link