Orin D'owo

Orin d'owó,orin dolà lo jẹ un wa dúpẹ o
Orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá (orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá)
Al'orin d'owó,orin dolà lo jẹ un wa dúpẹ o
Orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá (orin d'owó orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá)

Bi isẹ ba ti l'alubarika opẹ lo yẹ ki eru o da o
Orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá (orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá)
Àní bi isẹ ba ti l'alubarika ijó ló yẹ kẹrú ojó
Orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá (orin d'owó,orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá)

Olú ayé fuji mo gbe eré ta wi de o
Ọlọhun lo s'ọlà fuji bo ti rí ọ
Ayinde Wasiu ẹrú ń dúpẹ'
Bo ba wa dúpẹ ore agbà mi si ó
Amuda wa sukura mo dúpẹ-dúpẹ o
Gbogbo àwọn to tin lu fuji lati ijọ rí
La t'ayé aji saari,aye aji wéré
Ko to wa dori fuji ti isẹyin o

Bi isẹ ba ti l'alubarika ijo ló yẹ k'ẹrú ojó
Orin d'owó orin dolà lo jẹ un tun ọpẹ dá
Ìbà Sikiru mi ọmọ Abiba l'ọdọfin area
Ìbà Ajadi Ganiyu l'oluwọlé
Àwọn to kọ lu fuji lati aji wéré
Ayinde Muniru ọmọ Mayegun
Kao Aminu,Saka Laigbade mo la ó pe o
Mufu fuji la wà atí Ayinde the law,l'akarawu area
Ajadi lawa l'ewé iná o

Jibowu Barrister,Kasali Alani mi yọmi
Abinuwaye Basiru,Late Dauda mi Akanmu epo
Epo àkàrà n'ibadan ọ'run ẹ re
Akande Monsuru
Kótó wa dorí Agbaje lọla mi Barry Wonder mi o
Doctor Sikiru mi Ayinde Ade o
Barusati mí Ìbà ẹ ni mo se ó
Agbaje l'ọlá dèdẹgò ori ẹ sa l'ere tiyi padà
Ayinla Kollinton baba latika

Kebe Kwara mi ibà ni mo se ó
Adio Fatai,Ogidan Ololaaju
Ayinde Rahimi Bokotẹ
Akani Ramoni mi Abiodun
Hajji Lao Azeez l'agege ó
Iyanda Sawaba mí ewé nla ó
Akangbe Waheed ati Famusi mi Alamu aye ó
Ati Kabaka ní Ilorin afonja ó
Ati Sakariyau mí Danfo ó

Emi ọba fuji lo ma ń kí yín ó
K1 De Ultimate,akanda elédùmarè t'ayé nfẹ ó
Ẹ'yin to ń bọ' lẹ'yìn kẹ kí ará iwaju
Ará iwaju oni re lẹ o
A ó se fuji yi là fi l'owo lọ'wọ
A ó se fuji yi là l'owo lọ'wọ' (a ó se fuji yi là l'owo lọ'wọ)
A ó se fuji yi là l'owo lọ'wọ
A ó se fuji yi là l'owo lọ'wọ (a ó se fuji yi là l'owo lọ'wọ)

Walahi talahi Ayinde ó,mo f'ọlọhun búra ọrọ ni
Walahi talahi Ayinde ó,mo tún f'ọlọhun búra ọrọ ni
Ẹni má báwa du ọrọ yí o,a de Mecca awa le
Ọrọ yí ọ,ẹni ma báwa dù ọrọ yí o a ní tira tó dájú
Walahi talahi Ayinde ó
Ẹni ma báwa dù ọ'rọ' yí o,a ní tira tó gboju
Ọrọ yí ọ,ẹni ma báwa dù ọrọ yí o
A de Mecca awá lé

(Yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin yasin)
(Wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e,wadu e, wadu e,wadu e)

Motun f'ọlọhun búra Ayinde ó,Anọbi Muhamma
(Bàbá fa,bàbá fà,bàbá fa,bàbá fà,bàbá fa,bàbá fà, bàbá fa,bàbá fà,bàbá Fatimo)
Eyi tí mo wi yẹn
(Ọrọ ní,ọrọ ní,ọrọ ni,ọrọ ní,ọrọ ni,ọrọ ní,ọrọ ni,ọrọ ní,ọrọ ni)
(yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin,yasin yasin,yasin)

Million,million ní fi ó ojo ojúmọ' ké
Ọrọ yí ọ,ẹni ma bámi dù ọrọ yí o
A ni sense to m'ori pe
Òrò yí ọ,ẹni ma báwa dù ọrọ yí o
A de Mecca awá lé

Ẹ tún ban wípé bẹẹ noni (bẹẹ noni)
Ani ẹ ban wípé bẹẹ noni o (bẹẹ noni)
Ọlọhun Ọba ló ṣe àdéhùn yio (bẹẹ noni)
Baba God ló ṣe àdéhùn yí o (bẹẹ noni)
Pe òhun oni fí wa sílẹ fún ìyà jẹ o (bẹẹ noni)
Ọlọhun Ọba mu ìlérí ẹ ṣẹ (bẹẹ noni)
O ma se mu ìlérí ẹ ṣẹ ó (bẹẹ noni)
Gbogbo oni fuji kẹ majo (bẹẹ noni)
Kòní re ajo rẹyìn lọla Ọlọhun mi àmìn (bẹẹ noni)

Ẹyin lon di àkùkọ ọmọ Gbolahan àbí (bẹẹ noni)
Ẹyin lon di àkùkọ ọmọ Gbolahan Ayinde (bẹẹ noni)
Ẹ wí pé bẹẹ noni o (bẹẹ noni)



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link