Iwalewa

Iwa lewa omo eniyan, ko ba dakun toju iwa e
Iwa lewa omo eniyan, ko ba dakun toju iwa e

Iwa omo ni omo se ki n gbe
E to ju e da da
Iwa to ni ba dun, bami to ju e da da (da da)
Iwa yi lo soro
Lo se oun gbogbo ni mere mere banta
N ba to ju e
Iwa ni o ku oniwa ti o ba ti si anybody mo
Iwa se pataki (pataki)
A de le ba eni won ko n le
E kole bi iwa eni ni
Oniwa lo ni wa o
Iwa omo ni mu omo so ki ngbe

O ba dakun to ju e da da

Iwa lewa omo eniyan, o ba dakun to ju iwa e
Iwa lewa omo eniyan, o ba dakun to ju iwa e

Ara banbi jaye oba
Sope ijo ti ya fun orogbo
Ara banbi jaye oba
Sope ijo ti ya fun orogbo
E ki olukosun ayana ina
Sango ijo ti ya fun orogbo
Afi ni fun jo bomo loju oko oya
Sango ijo ti ya fun orogbo
Ko jeun ajanaku ma fi iyo si
Sango ijo ti ya fun orogbo
E fufu lele ya gi mo aya apata
Sango ijo ti ya fun orogbo
Bi o wo odo ariwo ata
Sango ijo ti ya fun orogbo
Bi o gun oke odo ariwo ata
Sango ijo ti ya fun orogbo
Ko fese mejeji damiru oko oya
Sango ijo ti ya fun orogbo
Awa na ti ri oba koso
Sango ijo ti ya fun orogbo

E ki olukosun ayana ina
Sango ijo ti ya fun orogbo
E ba mi ki olukoso ayana ina
Sango ijo ti ya fun orogbo
Ara banbi jaye oba
Sango ijo ti ya fun orogbo
Ara banbi jaye oba
Sango ijo ti ya fun orogbo



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link