Maa Logba Arami

E je ka oun to ba jora won, kafi we ra won
E je ka oun to ba jora won, kafi we ra won
Yeni next ko ba mi

Oun to ba n jo ra won la fi n we ra
Oun to ba n jo ra won la fi n we ra won
Ase buruku ema ku ara fu o
Ase baje ku ofo o
Mo loun to jora won la fi n we ra won
Ase buruku ema ku ara fu o
Ase baje ku ofo o
Won ran eni mejo wa pe e o
Won ran eni mejo wa pe e o
O ko merin leyin
Igba to ko merin nko
O se wi wo e wo
Bi o se gbigbe e gbe
Won ran eni merin wa pe e o
Won ran eni mejo wa pe e o
O se agidi o ko merin o
O se wi wo e wo
Bi o se gbigbe e gbe
E wo eni ti olopa mu
To loun o gbo oro
Toun o gba koro
Ibo lo wa to je ipe oba
A ni bo se wi wo e wo
Bi o se gbigbe e gbe

O n se agidi si won lowo ba ti se ise ti oti pari
E ni ti Olorun n gba fun o
Gbogbo eyan to ba gba fun
Won ti ri oju Olorun oba ni
A ni e wo eni ti olopa mu
To loun o gbo agolo
Oun o gba koro
Ibo lo wa to je ipe oba

Alagbaja ba la o
Alagbaja ba la o
Alagbaja ba la o
Inu aja lo n gbe
Olohu-un
Olohu-un
Olohu-un
Inu elede lo n gbe si
Ko gbe nu omo ojo ra bi ogede

Mo da yi gun na mo da yi gun na o
O wa da ki bata o, to n to oko lenu o
Mo ni mo da yi gun na mo da yi gun na o
O wa da ki bata o, to n to oko lenu o
E soro mi ke dake
Oun t'oluwa ba ti fun ni, a lo ti fun ni na
Eyi o pa kadara ofo
Omode yi o pe Ayinde

Maa logba arami, ma se bi o se wun mi o
Maa logba arami, ma se bi o se wun mi
Maa ma logba arami, ma se bi o se wun mi

Ise mi ni mo n se
Ohun mi ni mo n tele
Ona mi ni mo n rin
E ma f'ori we ori
Ke ma se tan ninu ise Olorun oba

Maa logba arami, ma se bi o se wun mi
Maa logba arami, ma se bi o se wun mi
Aranbanbi, ma se bi ose wun mi
Adegoro eyan oba, ma se bi ose wun mi



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link