Otunba Rotimi Ajanaku - Okepopo Area

Òkè poopó, òkè popó
Òkè poopó, òkè popó
Ẹní o mò wa ko ma se dùnbú wa
Ẹní o mò wa ko ma se dùnbú wa l'ọnà
Bo se irú ẹ, atẹ si
Òkè poopó, òkè popó
Òkè poopó, òkè popó
Ẹní o mò wa ko ma se dùnbú wa
Ẹní o mò wa ko ma se dùnbú wa l'ọnà
Bo se irú ẹ, atẹ si

Ní Lagos Ireland, ní mo fi re òkè pòpó area mi o
Tori Rotimi mi ọmọ T'ajanaku
Olúwa Rotimi mi ọmọ Victoria
Ọkọ Oyinlola babe mi ọmọ Falana
Ọlá baba Tunmise, Baba Femi, Baba Fọla Fọla
Owó Baba Feranmi

Aláṣẹ Delno group international
Aláṣẹ Delno properties
Ìwọ kan ma lagbalaba, Aláṣẹ Tunfem farms
Ọrẹ ti Dare, Dare Santana mi

Òkè poopó, òkè popó
Òkè poopó, òkè popó
Ẹní o mò wa ko ma se dùnbú wa
Ẹní o mò wa ko ma se dùnbú wa l'ọnà
Bo se irú ẹ, atẹ si

Koma ba mi tojú Alex ní Toronto mi o
Àti Kunle Rasheedi mi ọmọ mí K Rash min nko
Abi iwa pẹlẹ bí orí adẹ'tù ni ó
Ọkọ Oyinlola babe mi, kogba fún ẹ to

Olúwa Rotimi ó, Ọmọ Victoria
Aláṣẹ Dino yi ó, Ọmọ Victoria
Ọmọ T'ajanaku, Ọmọ Victoria
Olúwa Rotimi ó, Ọmọ Victoria

Dilno,Dilno, Dilno,Dilno ọmọ Victoria
Aláṣẹ dinoun yi o, Ọmọ Victoria
Eerin kọjá ẹran ahun bawi
Àjànàkú kọjá Ẹran ahun fọ'pa lu, ọmọ Victoria
Olúwa Rotimi ó, Ọmọ Victoria

Loke popó, Loke pòpó, Loke popó o
Loke popó, Loke popó, Loke popó o
Loke popó, Loke popó, Loke popó o



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link