Mode Mode
Modé, modé niti ewé adé ó (niti ewé adé)
Àní, modé, modé niti ewé adé (niti ewé adé)
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Motun de pẹ'lú odù mi timo fin jẹ leader ó
Ẹyin ará bi
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Motun de pẹ'lú odù mi timo fin jẹ leader ó
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Motun de pẹ'lú odù mi timo fin jẹ leader ó
Ẹyin ará bi
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Motun de pẹ'lú odù mi timo fin jẹ leader ó
Éle sìse ẹyẹ, éle sìse ẹyẹ
Éle sìse ẹyẹ, éle sìse ẹyẹ
Afopina fira rẹ wé ẹyẹ, éle sìse ẹyẹ
Wele sìse ẹyẹ, wéle sìse ẹyẹ
Afopina fira rẹ wé ẹyẹ, wéle sìse ẹyẹ
Éle sìse ẹyẹ, omà le sìse ẹyẹ
Afopina fira rẹ wé ẹyẹ, éle sìse ẹyẹ
Wéle sìse ẹyẹ, wéle sìse ẹyẹ
Afopina fira rẹ wé ẹyẹ, éle sìse ẹyẹ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Kínní àgbàlagbà nlé lábẹ asọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Kínní àgbàlagbà nlé lábẹ asọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Motún dé bímọ seń dé
Mio lèè rí kín mámà sọ Arabambi
Ìwà ìbàjé gbaye kan
Larin awon Obìnrin ọmọ wa
Ẹtọju eni ó nítorí ọlá wá
Ẹwà t'ólóhùn Ọba se f'obinrin
Pè koma wú ni lórí
Paapa julọ ọmọ Yorùbá
Ta jọmọ Africa,ta lafinju
Kama se jẹ k'ẹwà obajẹ
Oorúkọ sàgbà oyè
Ilé tán bí oníkálukú lon wùni lórí
Irán t'okunrin má wo ni ìgbẹ̀yìn
Tío dùnnú toma mújójó
Ẹma fi se sààrá, kẹ fi wolẹ' yantú-rúrú-rúrú
Ẹyin Ọmọge ìsèyín, ẹyin ni moń bawi
Ẹjẹ a yà rawa l'ọpọlọ
Torí eni kọ, torí ọ'la ni
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Kínní àgbàlagbà nlé lábẹ' asọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Kínní àgbàlagbà nlé lábẹ' asọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Mo dẹrujẹjẹ, mo dẹrujẹjẹ ó
Ayinde Ade mo dẹrujẹjẹ
Mo dẹrujẹjẹ, mo dẹrujẹjẹ ó
Mo dẹrujẹjẹ, momọ ẹrujẹjẹ
Ibi abá pè lórí aifi ìdí ẹ lẹlẹ o
Ẹyin ará bí
Mo dẹrujẹjẹ, mo dẹrujẹjẹ ó
Mo dẹrujẹjẹ, mo dẹrujẹjẹ ó
Ibi abá pè lórí
Akima ifi ìdí ẹ lẹlẹ o (a ifi ìdí ẹ lẹlẹ o)
Àtẹwọ mi ni ya-ya
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Àtẹwọ mi ni ya-ya o
(Àtẹ'wọ mi ni ya-ya)
Àtẹ'wọ mi ni ya-ya o
(Àtẹ'wọ mi ni ya-ya)
Ní máfi f'ore mi dupẹ fún Ọlóhùn Ọba mi
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Ore to se funmi ilahi Ọlọhun Ọba mo dúpẹ'
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Gbogbo lílọ bibọ mí Arabambi lojújúmọ'
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Lórí ẹbímí, lórí ọmọ mi, lórí ẹgbẹ
(Àtẹwo mi ni ya-ya)
Mon kó ẹgbẹ' jáde lojújúmọ'
Mon kó wọn lọ, kò wọn bọ
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Lórí gbogbo olólùfẹ' mí kakiri agbanla ayé
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Modupẹ ore to se funmi Ọlọhun Ọba mí
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Àtẹwọ mi ni ya-ya ó
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Onílù mi àbi ẹsún
Orun wẹ, níwájú adajọ
Onílù mi àbí ẹsún
Orun wẹẹ, níwájú adajọ
Onílù mi àbí ẹsún
Orun wẹ, níwájú adajọ
Onílù mi àbí ẹsún
Orun wẹẹ, níwájú adajọ
Fuji mi, Fuji mi kólé tán, kólé tán ó
Torí ẹ lose daleeba o
Ọlọhun lo f'adùn sí Fuji mi ò
Ẹyin ará bí
Fuji mi, Fuji mi kólé tán, kólé tán ó
Torí ẹ lose daleeba o
Ọlọhun lo f'adùn sí Fuji mi ò
Ogbọ bímo seń wí
Ọlọhun Ọba lose ẹwà Fuji yí fún Ayinde o
Àwọn tó jáye lana wọn lu Fuji yi dáàda
Kobaajẹ lori àná
Kọni baajẹ lórí èmí Arabambi o
Titi lailai ní Fuji ama dún
Nipelé, nipelé ni àbẹ rí Ayinde Arabambi
Fuji mi, Fuji mi kólé tán, kólé tán ó
Torí ẹ lose daleeba o
Ọlọhun lo f'adùn sí Fuji mi ò
Ẹwi kin gbọ
Fuji mi, Fuji mi kólé tán, kólé tán ó
Torí ẹ lose daleeba o
Ọlọhun lo f'adùn sí Fuji mi ò
Àtẹwọ mi ni yaa-ya
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Àatẹwọ mi ni ya-ya o
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Lori ore to se fún Fuji mi Ayinde Ade
(Àtẹ'wọ' mi ni ya-ya)
Alori ore to se fún Fuji mi Ayinde Ade o
(Àtẹ'wọ' mi ni ya-ya)
Moma dúpẹ' Ọlọhun Ọba ó Arabambi
(Àtẹ'wọ' mi ni ya-ya)
Gbogbo oni Fuji ẹma jo ẹma yọ Ọba de
(Àtẹ'wọ' mi ni ya-ya)
Oni Fuji kakiri àgbànla ayé ẹma yọ o
(Àtẹ'wọ' mi ni ya-ya)
Àatẹwọ mi ni ya-ya o
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Àní, modé, modé niti ewé adé (niti ewé adé)
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Motun de pẹ'lú odù mi timo fin jẹ leader ó
Ẹyin ará bi
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Motun de pẹ'lú odù mi timo fin jẹ leader ó
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Motun de pẹ'lú odù mi timo fin jẹ leader ó
Ẹyin ará bi
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Mobò, mobò ni tọrọ àbọ' ó
Motun de pẹ'lú odù mi timo fin jẹ leader ó
Éle sìse ẹyẹ, éle sìse ẹyẹ
Éle sìse ẹyẹ, éle sìse ẹyẹ
Afopina fira rẹ wé ẹyẹ, éle sìse ẹyẹ
Wele sìse ẹyẹ, wéle sìse ẹyẹ
Afopina fira rẹ wé ẹyẹ, wéle sìse ẹyẹ
Éle sìse ẹyẹ, omà le sìse ẹyẹ
Afopina fira rẹ wé ẹyẹ, éle sìse ẹyẹ
Wéle sìse ẹyẹ, wéle sìse ẹyẹ
Afopina fira rẹ wé ẹyẹ, éle sìse ẹyẹ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Kínní àgbàlagbà nlé lábẹ asọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Kínní àgbàlagbà nlé lábẹ asọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Motún dé bímọ seń dé
Mio lèè rí kín mámà sọ Arabambi
Ìwà ìbàjé gbaye kan
Larin awon Obìnrin ọmọ wa
Ẹtọju eni ó nítorí ọlá wá
Ẹwà t'ólóhùn Ọba se f'obinrin
Pè koma wú ni lórí
Paapa julọ ọmọ Yorùbá
Ta jọmọ Africa,ta lafinju
Kama se jẹ k'ẹwà obajẹ
Oorúkọ sàgbà oyè
Ilé tán bí oníkálukú lon wùni lórí
Irán t'okunrin má wo ni ìgbẹ̀yìn
Tío dùnnú toma mújójó
Ẹma fi se sààrá, kẹ fi wolẹ' yantú-rúrú-rúrú
Ẹyin Ọmọge ìsèyín, ẹyin ni moń bawi
Ẹjẹ a yà rawa l'ọpọlọ
Torí eni kọ, torí ọ'la ni
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Kínní àgbàlagbà nlé lábẹ' asọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Kínní àgbàlagbà nlé lábẹ' asọ
Alosọ pénpén ẹ padi yín mọ
Mo dẹrujẹjẹ, mo dẹrujẹjẹ ó
Ayinde Ade mo dẹrujẹjẹ
Mo dẹrujẹjẹ, mo dẹrujẹjẹ ó
Mo dẹrujẹjẹ, momọ ẹrujẹjẹ
Ibi abá pè lórí aifi ìdí ẹ lẹlẹ o
Ẹyin ará bí
Mo dẹrujẹjẹ, mo dẹrujẹjẹ ó
Mo dẹrujẹjẹ, mo dẹrujẹjẹ ó
Ibi abá pè lórí
Akima ifi ìdí ẹ lẹlẹ o (a ifi ìdí ẹ lẹlẹ o)
Àtẹwọ mi ni ya-ya
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Àtẹwọ mi ni ya-ya o
(Àtẹ'wọ mi ni ya-ya)
Àtẹ'wọ mi ni ya-ya o
(Àtẹ'wọ mi ni ya-ya)
Ní máfi f'ore mi dupẹ fún Ọlóhùn Ọba mi
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Ore to se funmi ilahi Ọlọhun Ọba mo dúpẹ'
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Gbogbo lílọ bibọ mí Arabambi lojújúmọ'
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Lórí ẹbímí, lórí ọmọ mi, lórí ẹgbẹ
(Àtẹwo mi ni ya-ya)
Mon kó ẹgbẹ' jáde lojújúmọ'
Mon kó wọn lọ, kò wọn bọ
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Lórí gbogbo olólùfẹ' mí kakiri agbanla ayé
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Modupẹ ore to se funmi Ọlọhun Ọba mí
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Àtẹwọ mi ni ya-ya ó
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Onílù mi àbi ẹsún
Orun wẹ, níwájú adajọ
Onílù mi àbí ẹsún
Orun wẹẹ, níwájú adajọ
Onílù mi àbí ẹsún
Orun wẹ, níwájú adajọ
Onílù mi àbí ẹsún
Orun wẹẹ, níwájú adajọ
Fuji mi, Fuji mi kólé tán, kólé tán ó
Torí ẹ lose daleeba o
Ọlọhun lo f'adùn sí Fuji mi ò
Ẹyin ará bí
Fuji mi, Fuji mi kólé tán, kólé tán ó
Torí ẹ lose daleeba o
Ọlọhun lo f'adùn sí Fuji mi ò
Ogbọ bímo seń wí
Ọlọhun Ọba lose ẹwà Fuji yí fún Ayinde o
Àwọn tó jáye lana wọn lu Fuji yi dáàda
Kobaajẹ lori àná
Kọni baajẹ lórí èmí Arabambi o
Titi lailai ní Fuji ama dún
Nipelé, nipelé ni àbẹ rí Ayinde Arabambi
Fuji mi, Fuji mi kólé tán, kólé tán ó
Torí ẹ lose daleeba o
Ọlọhun lo f'adùn sí Fuji mi ò
Ẹwi kin gbọ
Fuji mi, Fuji mi kólé tán, kólé tán ó
Torí ẹ lose daleeba o
Ọlọhun lo f'adùn sí Fuji mi ò
Àtẹwọ mi ni yaa-ya
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Àatẹwọ mi ni ya-ya o
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Lori ore to se fún Fuji mi Ayinde Ade
(Àtẹ'wọ' mi ni ya-ya)
Alori ore to se fún Fuji mi Ayinde Ade o
(Àtẹ'wọ' mi ni ya-ya)
Moma dúpẹ' Ọlọhun Ọba ó Arabambi
(Àtẹ'wọ' mi ni ya-ya)
Gbogbo oni Fuji ẹma jo ẹma yọ Ọba de
(Àtẹ'wọ' mi ni ya-ya)
Oni Fuji kakiri àgbànla ayé ẹma yọ o
(Àtẹ'wọ' mi ni ya-ya)
Àatẹwọ mi ni ya-ya o
(Àtẹwọ mi ni ya-ya)
Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.