Gbojule

Mo ma ri ore
Mo ma ri ore to po
Oro ti o niye
Mo ma ri ore
Mo ma ri ore to po
Oro ti o niye

Amin o ase!
Amin o ase!
Amin oo

Sebi awa ri Baba gb'ojule (Sebi awa ri Baba gb'ojule)
Sebi awa ri Baba gb'ojule (Sebi awa ri Baba gb'ojule)
Sebi awa ri Baba f'eyinti (Baba f'eyinti)
Bee na laa ri
Bee naa a se
Sebi awa ri Baba gb'ojule

Sometime ago, living in the darkness
Ireti d'opin o
Ko ma s'enikan a sa ba o
Ife ti o lakawe (ko lakawe) o, lo wa mi ri (lo wa mi ri)
O tan imole s'ona mi
O gbe mi s'ejika wa'le
Iyanu yen si wa
O si ma a wa

Tori awa ri Baba gb'ojule
Sebi awa ri Baba gb'ojule, o daju saka (Sebi awa ri Baba gb'ojule)
Sebi awa ri Baba gb'ojule (Sebi awa ri Baba gb'ojule)
Sebi awa ri Baba f'eyinti (Baba f'eyinti)
Bee naa la ri
Bee naa a se
Sebi awa ri Baba gb'ojule

But right now
My path is bright gan ni (O bright gaan)
Ife to se yen wa sibe, ko le yi pada laye o
Emi yo layo ninu Re, Alasepe oore
O le se ju bee lo o, Olododo ni Baba
Olutoju mi si wa, yo si ma a be
Emi ma ri Baba gb'ojule

Sebi awa ri Baba gb'ojule, dajudaju (Sebi awa ri Baba gb'ojule)
Awa ma ri Baba gb'ojule o, ki i d'oju tini o (Sebi awa ri Baba gb'ojule)
(Sebi awa ri Baba gb'ojule)
Olubukun, Olufunni, lawa f'eyinti
Bee naa la ri
Bee naa a se
Sebi awa ri Baba gb'ojule

Bi eru wa, sibe o wa, ko le yi pada lailai
Sebi awa ri Baba gb'ojule
Alaanu, Olupese, Oludande, Oloore ni
Sebi awa ri Baba gb'ojule
Mo ri oore, oro to po, ileri Re a se mo mi lara
Sebi awa ri Baba gb'ojule
Mo gbeke le, mo mo A a se e, O ti so bee, oro Re ki i ye, ohun ni Baba
Sebi awa ri Baba gb'ojule



Credits
Writer(s): Sola Allyson
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link