#Yoo Daa

Ta le ni naa ti n so pe ko le da yoo da
Ta le ni naa ti n so pe aye mi o le dide mo
Ta le ni naa ti n so pe o ti tan oooo haa
Wo ni ko ri pé oluwa ma dun gan, o si po oo
Ta le ni naa ti n so pe ko le da yoo da
Ta le ni naa ti n so pe aye mi o le dide mo
Ta le ni naa ti n so pe o ti tan oooo haa
Wo ni ko ri pé oluwa, ma dun gan o si po oo

Eni to mumi bo lati ipele mi o ma ga
O hun lo mumi rin la la e fe se ko
O ma ga
Ohun lo mumi duro mi o le subu o laye laye
Wo mi ko ripe alanu yi ma ga gan o ma ga
Ohun lo da mi bi adaran, je oluso aguntan mi
Ohun lo n re mi lo n to isise mi beni
Oro re fitila lese mi imole lona mi
Ati pe mi wole imole baba bẹni

Ta le ni naa ti n so pe ko le da yoo da
Ta le ni naa ti n so pe aye mi o le dide mo
Ta le ni naa ti n so pe o ti tan oooo haa
Wo ni ko ri pé oluwa ma dun gan o si po oo

Instruments

Credits
Writer(s): Sola Allyson
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link