Maje Kope Jesu

Ma je kope Jesu
Ko ba mise
Ma je kope Jesu
Ko ba mise
To ba lo peju
Aye a soro odi si mi oo
Ma je kope Jesu
Ko bami se

Ma je kope Jesu
Ko ba mise
Ma je kope Jesu
ko ba mise
To ba lo peju
Aye a soro odi si mi oo
Ma je kope Jesu
Ko bami se

Gbogbo ileri alangba
Ko ju idobale lo
Maje ka'ye sofunmi pe
Gbogbo Lala Mi
Oju kan lo n ja si
Wa fi anu gbemi jade
Aiye ti mo mi mo oo
Maje kope Jesu
Ko ba mi se

Ma je kope Jesu
Ko ba mise
Ma je kope Jesu
Ko ba mise
To ba lo peju
Aye a soro odi si mi oo
Ma je kope Jesu
Ko bami se

Gbogbo awon to n woju re fun omo
Baba bawa dawon lo'hun
Awon to'n fe aya at'oko rere
Ba wa se fun won
Gbogbo awon to fe se rere
Silekun fun won ooo
Maje ko pe Jesu
Ko bawa se

Ma je kope Jesu
Ko ba mise
Ma je kope Jesu
Ko ba mise
To ba lo peju
Aye a soro odi si mi oo
Ma je kope Jesu
Ko bami se

Oru to su dede
Mo mo pe ile fere mo na
Oru to su dede
To bamo afore funmi
Oru to su dede
Mo mo pe ile fere mo na
Oru to su dede
To bamo afore funmi

Oru yi ma gun ooo
Sugbon odi dandan ki ile mo
Bekun bape titi dale
Ayo nbo lowuro,
Ben'yan ba fomije fun rugbin
Odi dandan kofa'yoka
Bi ikuku ba koja lo
Odamiloju imole atan

Oru to su dede
Mo mo pe ile fere mo na
Oru to su dede
To bamo afore funmi

To bamo a fore funmi
To ba mo afore funmi
A o pe mi ni akorede
To ba mo afore funmi
Idahoro tan lo'ruko Jesu
To ba mo afore funmi
Ide ja madi ominira
To ba mo afore funmi
Oru oo
Oru to su dede
Mo mo pe ile fere mo na
Oru to su dede
To bamo a fore funmi

Ki len fo'lorun mi pe
Baba to lagbara lori ohun gbogbo
Ki len fo'lorun mi pe
Baba to lagbara lori ohun gbogbo
Dragoni aiye re ti subu lule
Baba to lagbara lori ohun gbogbo
Osubu lule ko male dide mo
Baba to lagbara lori ohun gbogbo
Iyagan aye re ti dopin o
Baba to lagbara lori ohun gbogbo
Aisan salo otidominira
Baba to lagbara lori ohun gbogbo
Hamani aye wa sera re
Baba to lagbara lori ohun gbogbo
Ki len fo'lorun mi pe
Baba to lagbara lori ohun gbogbo
Olagbara lori gbogbo oro re
Baba to lagbara lori ohun gbogbo
Ki len fo'lorun mi pe
Baba to lagbara lori ohun gbogbo

Bukun fun wa nile
Bukun fun wa loko
Bukun fun wa ni irin ajo wa
Bukun fun wa nibi gbogbo

Bukun fun wa nile
Bukun fun wa loko
Bukun fun wa ni irin ajo wa
Bukun fun wa nibi gbogbo

O bukun fun Isaac nile
O bukun fun Abrahamu loko
Opade Jakobu
O so di Isreali oo
Bukun fun wa nibi gbogbo

Bukun fun wa nile
Bukun fun wa loko
Bukun fun wa ni irin ajo wa
Bukun fun wa nibi gbogbo

Maba mi lo
Ma sin mi lo o
Ona aye mi jina
Ma ba mi lo
Saju aye mi o
Keyin aye mi o
Nirin ajo aiye mi
Iwo ni mo fe ri nibe
Saju aiye mi o
Keyin aye mi o
Nirin ajo aiye mi
Iwo ni mo fe ri nibe

Dugbe, dugbe
Onja kiri nibi gbogbo
Eni o ba koyo
Lo yo ninu ewu
Ajo la'ye Jesu
Arin yege ni ko mu wa rin
Oluwa
E ma sowa o
Ajo la'ye Jesu
Arin yege ni ko mu wa rin
Oluwa, e ma sowa o

Ewu nibi gbogbo o
Ko seni tale gbekele mo
Iya nse omo re
Awon ore nta rawon o
Iwo la wa ni da'bobo aye wa o
Iya nse omo re
Awon ore ta n ra won o
Iwo la wa ni
Da'bobo aye wa o

Maba mi lo
Ma sin mi lo o
Ona aye mi jina
Ma ba mi lo
Saju aye mi o
Keyin aye mi o
Nirin ajo aiye mi
Iwo ni mo fe ri nibe
Saju aiye mi o
Keyin aye mi o
Nirin ajo aiye mi
Iwo ni mo fe ri nibe

Funmi ni eri
Funmi ni eri o
Funmi ni eri Jesu
Funmi ni eri tuntun

Funmi ni eri
Wa funmi ni eri o
Funmi ni eri Jesu mi
Funmi ni eri tuntun

Funmi ni eri
Funmi ni eri o
Funmi ni eri Jesu
Funmi ni eri tuntun

Funmi ni eri
Funmi ni eri o
Funmi ni eri Jesu
Funmi ni eri tuntun

Onjoba lo o
Onjoba lo o
On joba lo
Onise rere njoba lo
Onjoba lo o
Onjoba lo o
Onjoba lo
Ijoba re ko dawo duro

Onjoba lo o
Onjoba lo o
On joba lo
Onise rere njoba lo
Onjoba lo o
Onjoba lo o
Onjoba lo
Ijoba re ko dawo duro

Onjoba lo o
Onjoba lo o
On joba lo
Onise rere njoba lo
Onjoba lo o
Onjoba lo o
Onjoba lo
Ijoba re ko dawo duro

Onjoba lo o
Onjoba lo o
On joba lo
Onise rere njoba lo
Onjoba lo o
Onjoba lo o
Onjoba lo
Ijoba re ko dawo duro



Credits
Writer(s): Bose Adekunle
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link