Jesu Ni Wura

Jesu ni wura iyebiye
O toju mi ni gba gbogbo
Ko je fimi sile funya je
Ose Jesu

Jesu ni wura iyebiye
O toju mi ni gba gbogbo
Ko je fimi sile funya je
Ose Jesu

Baba fun alaini baba
Olugbeja omo orukan
Oko fun opo
Olugbeja gbogbo agbaye
Iwo lon toju mi o

Jesu ni wura iyebiye
O toju mi ni gba gbogbo
Ko je fimi sile funya je
Ose Jesu

Oluwa mo gbe o ga o
Oluwa mo gbe o ga o
Awon orun bami yin o o
Pe ose
Awon orun bami yin o o
Pe ose

Oluwa mo gbe o ga o
Oluwa mo gbe o ga o
Awon orun bami yin o o
Pe ose
Awon orun bami yin o o
Pe ose

Oluwa mo gbe o ga o
Oluwa mo gbe o ga o
Awon orun bami yin o o
Pe ose
Awon orun bami yin o o
Pe ose

Olorun ipe
Olorun ipe mi
Oku ise lori ipe mi
Toje ko dojuru

Olorun ipe
Olorun ipe mi
Oku ise lori ipe mi
Toje ko dojuru

Onpeni ti nsola
Olorun olodumare
Arani waye banise
Tin so'lorun Abrahamu
Eri olola baba mi
Ti n pa majemu mo o
Oku ise lori oro mi
Toje ko dojuru

Olorun ipe
Olorun ipe mi
Oku ise lori ipe mi
Toje ko dojuru

Emi ni, emi ni
Emi ni ma se beru
Olorun baba
Olorun omo
Olorun emi mimo
Ema ku agbaalemi
Eku ise, lori ipe mi
Te je kodojuru

Olorun ipe
Olorun ipe mi
Oku ise lori ipe mi
Toje ko dojuru

Olorun ipe
Olorun ipe mi
Oku ise lori ipe mi
Toje ko dojuru

Ibi ofa'nu gbe mi de
Ni mo wa yi o baba
Olorun o oku ise re

Ibi ofa'nu gbe mi de
Ni mo wa yi o baba
Olorun o oku ise re

Ogbon mi ole se
Anu re lo bami se
Olorun o oku ise re

Ibi ofa'nu gbe mi de
Ni mo wa yi o baba
Olorun o oku ise re

Motidi ominira
Ninu Jesu
Motidi ominira
Ninu apata ayeraye
Aiye
Esu
Ese
Kole ri mi gbe se mo o
Ebami yo
Eki mi ku orire

Bo'mo ba soyin di ominira, e
O do'minira nitoto
Ati bo o ninu igbekun esu
Oforuko tuntun pewa
Hephzibah
Beulah lo so wa oo
O da wa laworan re
Kileri ko le se

Motidi ominira
Ninu Jesu
Motidi ominira
Ninu apata ayeraye
Aiye
Esu
Ese
Kole ri mi gbe se mo o
Ebami yo
Eki mi ku orire

Efun pe na kikan
Ipe ihinrere
Kodun jake jado
Leti gbogbo eda

Odun idasile tide
Pada, elese pada a a
Odun idasile tide
Pada elese pada

Eki mi ku oriire
Eki mi ku oriire

Bami lowo
Kin ba e lowo
Eki mi ku oriire
Oju koju, arira layo
Eki mi ku oriire
Ide ja, adominira
Eki mi ku oriire
Jericho wo, ajaga ja
Eki mi ku oriire
Orin isegun la o ma ko
Eki mi ku oriire
Eba mi yo, eki mi ku orire

Motidi ominira
Ninu Jesu
Motidi ominira
Ninu apata ayeraye
Aiye
Esu
Ese
Kole ri mi gbe se mo o
Ebami yo
Eki mi ku orire

Motidi ominira
Ninu Jesu
Motidi ominira
Ninu apata ayeraye
Aiye
Esu
Ese
Kole ri mi gbe se mo o
Ebami yo
Eki mi ku orire

Motidi ominira
Ninu Jesu
Motidi ominira
Ninu apata ayeraye
Aiye
Esu
Ese
Kole ri mi gbe se mo o
Ebami yo
Eki mi ku orire



Credits
Writer(s): Bose Adekunle
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link