Major General Adebaye

Mo wa ṣe'ba gbogbo agba tin bẹ ni'waju mi dede omo awo patapata
Ile ni mo wa
(Àní ki Adede gbọ)
Irin ajo la wa
(Àní ki Adede gbọ)
London la wa
(Àní ki Adede gbọ)
Paper ni mo ka
(Àní ki Adede gbọ)
Wipe
Adeyinka Adebayọ lo tun wa j'oye
Major General l'oye tuntun tan gbefun

Major General Adeyimika Adebayọ
Baba Nikẹ onitemi
Baba Gboyega
Ọkọ Modupẹ
Iye gidi ni'le

Major General
Major General ọmọ Adebayọ ni
Awo Ẹkọ, ọmọ'ba onitemi atata ire
London la wa, la wa gbọ wipe
Adeyimika Adebayọ ìyẹn lo tu wa j'oye
Major General l'oye tuntun tan gbefun

Adeyimika
(Orire o ni ti ẹ)
Adebayọ
(Orire o ni ti ẹ)
Ọ ṣi ti ṣi f'ọlọrun edumare
(Orire o ni ti ẹ)
Ma miliki lọ, kò s'ewu rara
(Orire o ni ti ẹ)
No more people's ti ya were, ko s'ewu l'ẹgbẹrun ọpẹ nu ọbẹ
(Orire o ni ti ẹ)
Adeyimika Adebayọ mi
(Orire o ni ti ẹ)
Major General
(Orire o ni ti ẹ)
Awo Major General Yakubu Gowon ni
(Orire o ni ti ẹ)
Ọkọ Modupẹ
(Orire o ni ti ẹ)



Credits
Writer(s): Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link