Akanbi Ogun

Mo gbọ pọrọ lagbẹdẹ
Àgbẹ'dẹ lo n lu rin
Mo gbọ garara lagbẹdẹ
Àgbẹ'dẹ lo n lu rin
Mo gbọ rọmọ òwu lagbẹdẹ
Àgbẹ'dẹ lo n lu rin

Mo ṣe barakan bi ọmọ ogun mi o
The director, Isalẹ Imale trading company
Baba Wasiu mi atata, ọkọ Alhaja tiwa ni
Oronile padi mi
Gbogbo ara ile mi
Ẹ ma pèmí l'Akanbi ọgọ ma o
Ara ile mi pata
Ẹ ma pèmí l'Akanbi ọgọ ma o

Akanbi o gọ
Oju lọrun ti fú rawa
Akanbi o gọ
Oju lọrun ti fú rawa
Ara ile mi
Ẹ ma pèmí l'Akanbi ọgọ ma o
Anifowose, la o pe Akanbi o
Anifowo', Anifowo'
Anifowose la o p'Akanbi o

Mama o ma lorukọ meji ti o s'ọmọ
Baba o ma lorukọ meji ti o s'ọmọ
Anifowo', Anifowo'
Anifowose la o p'Akanbi o

Akanbi Ogunmi Tijani
Sheu Tijani
Alhaji Lọla Tijani
Sheu Tijani
Awọn Alhaji tiwa ni
Sheu Tijani
Baba ni ẹ ma na Tijani
Sheu Tijani
Iya ni ẹ ma na Tijani
Sheu Tijani



Credits
Writer(s): Sunny Ade
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link