Omo Mi a Se Rere

Omo mi a ye, won o ni ku fun mi,
Loruko Jesu o, ma jere omo mi ah

Omo mi a ye, won o ni ku fun mi,
Loruko Jesu o, ma jere omo mi

Tori ati ko pe,
Obinrin mi yo dabi ajara Eleso rere ninu ile mi,
Ati ko pe awon omo mi
A dabi igi Olifi yi tabili mi ka,
Ati ko pe mi o ni bimo fun wahala,
Ati ko pe emi ni yo je ise owo mi,
Ati ko pe yo dara fun mi o,
Loruko Jesu o ma jere omo mi, aha

Omo mi a ye, won o ni ku fun mi,
Loruko Jesu o, ma jere omo mi

Abiyamo gbogbo - e pariwo pe,
Omo mi e o se rere loruko Jesu,
Omo mi e o lu aluyo loruko Jesu,
Omo mi aseyori le ma se,
Mo sotele sinu aye yin, e o deni nla,
E o deniyan pataki,
Omo mi, e o se rere loju aye mi,
You shall prosper Ah ah

Omo mi a ye, won o ni ku fun mi,
Loruko Jesu o, ma jere omo mi

Oluwa mo kepe o,
Lori omo mi, bami gbe won soke o,
Fun won logbon, se won lolori ire,
Je ko dara fun won larin egbe, larin ogba o,
Je ki won rowo yo, mu won tayo,
Je ko dara fun won,
Loruko Jesu kemi ma foju sunkun won aha

Omo mi a ye, won o ni ku fun mi,
Loruko Jesu o, ma jere omo mi

Omo ni ini Oluwa, omo inu lere re o,
Gege bofa ti ri lowo alagbara,
bena ni awon omode,
Loruko Jesu omo mi e o se rere,
Ipo ti ngo le de, loruko Jesu eyin omo mi a de be o
Ohun rere temi o le se o,
Loruko Jesu eyin omo mi a se ju be lo,
Tori ati ko pe Isaaki o tobi ju Abraham lo,
A tun ko pe Jakobu o di orile ede nla,
Eyin omo mi loruko Jesu e o po ju mi lo,
E o ga ju mi lo, aseyori yin a ju temi lo,
Loruko Jesu e o ni ku mo mi lori ah aha

Omo mi a ye, won o ni ku fun mi,
Loruko Jesu o, ma jere omo mi

Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga.
Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga.

Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga.
Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga.

Jehovah nissin gbadura fomo mi gbe won ga.
Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga.

Mu won dagba, mu won wulo fun ogo re.
Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga.

Je ki won laluyo je ko dara fun won o, Olorun.
Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga.

Ticket ogo, Emi Mimo fi fun awon omo mi
Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga.

Gbogbo ota omo mi, loruko Jesu e di awati o.
Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga.

Loruko Jesu ni mo so
Eyin omo mi e o se rere.

Loruko Jesu ni mo pariwo
Eyin omo mi e o se rere.

Aluyo aluyo, aseyori,
Ibunkun opolopo, loruko Jesu ko je teyin omo mi.

Mo wi be Oluwa o gbadura fomo mi gbe won ga

Ariwo ayo, lori omo mi,
Ohun ayo ni ngo ma se,
Loruko Jesu eyin omo mi a se rere laye

Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga.

Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga
Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga

Je ki won laluyo je ko dara fun won o, Oluwa.
Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga

Gbe won soke so won dolorire laye
Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga

Gbe won soke o je ko dara fun won laye baba
Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga

Ticket ogo, Emi Mimo fi fun awon omo mi
Oluwa o, gbadura fomo mi gbe won ga



Credits
Writer(s): Aderemi Hezekiah Ademoroti
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link