Mo Ti L'oluwa

Mo ti l'Oluwa ni baba o
Ire ayo ninu ile mi

Mo ti l'Oluwa ni baba o
Ire ayo ninu ile mi

A ki loko ka fowo komi
Jesu Oluwa o nipin mi

A ki loko ka fowo komi
Jesu Oluwa o nipin mi

A ki loko ka fowo komi
Jesu Oluwa o nipin mi

Mi o gbodo ni Oluwa o
Ki ntun ma taraka jeun

Mo ni Jesu l'Oluwa
Ire ayo ninu ile mi.

Ariwo ayo lodede mi
Jesu Oluwa o nipin mi

Mo ni Jesu l'Oluwa
Ibanuje o si loro mi.

Ani ki le wi.
B'Oluwa ti nbe, t'emi re si wa,
A dara fun mi, a dara fun mi o,
Laye kan ti mo wa, ma a se rere.

O da mi loju, maa kuro ni Lodebari- mo nlo safin Oba,
Lati lo mu ayanmo mi se,
Akoko idaduro ti tan, mo nwonu ogo lo,
Ayanmo mi, o ya jade larin eniyan lasan,
Wonu ise rere lo pade olore.



Credits
Writer(s): Aderemi Hezekiah Ademoroti
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link