IRI SE

Bi ri ba ti se
Ara a ma tu ni ni
Bojo ba ti ro
Ara a maatu ni ni
Ba te gun ba fe,ara a ma tu ni ni
lri orun se lemi lori mo gba ltura, lri orun se lemi lori mogba itura
Iri se
Iri orun se lemi
Lori o, lri orun se sayemi mogba itura

Iri orun se lemi lori
Ogo farahan moti bo
Iri orun se lemi lori aye me dara mo gba itura
Ibanuje mi ana Erin lopada wa jasi
Ogbaso egan lara mighti orun se lemi lori moboo moyege
Ayemidara
Moyege
Moyege loruko jesu moyege
lri orun se lemilori ogo farahan motibo
lri orun se lemi lori ayemi dara mogba itura
Iri orun se lemi lori
Mobo lowo ogun ose
lri orun se lemi lori ayemi dara mogba itura
Ati fun mi ni itura pipe
lri orun se lemi lori ayemi dara mogba itura
Ide mi ti ja baba oti mumi bo mo booo mo bo tomo toko



Credits
Writer(s): Ifeoluwa Olamigoke
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link