MODUPE ORE

Alaarun opolo ole dupe ore baba
Alaarun opolo ole moun ti o n se omumi ranti adete mewa ti
O wo San sugbon okan lowa dupe okan to dupe yi ori anu gba mi
O ni salai mo re re layemi o
Ore sisun ore jiji kose fowora aanu ni morigba o ose Oluwa

Modupe ore baba se
Modupe ore mele salai
Mo re

Emi oni sa
Emi Oni sa lai
Emi Oni sa lai
More baba

Amope wa
Fun ore to se
Ore ririje
Ore ririmu
Adupe ore re
Baba
Ose ose ose
Oma je ka gbomosin
Oma je ka gbaya sin
Ti le tebi tara lati january titi de December
Oya wa lenu opawa mo
O ose ose ose

Kabioosi oba to mu
Majemu se o, eledumare
Akiikitan, akaikatan ni o
Oyi pada ri beelo si ni maayi pa da ni gbogbo ojo
Oba to n mu ojo ro lakoko re obato mu ogbele n wa



Credits
Writer(s): Ifeoluwa Olamigoke
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link