Zakat

Mo nyo zakat ninu owo mi, mofi tele, ase Allahu oba
Pe kama gbagbe alaini ati awon atoroje
Eni nyo zakat ari esan gba, dajudaju

Mo nyo zakat ninu owo mi, mofi tele, ase Allahu oba
Pe kama gbagbe alaini ati awon atoroje
Eni nyo zakat ari esan gba, dajudaju

Mo nyo zakaaaaa

Mo nyo zakat ninu owo mi, mofi tele, ase Allahu oba
Pe kama gbagbe alaini ati awon atoroje
Eni nyo zakat ari esan gba, dajudaju

Mo nyo zakat ninu owo mi, mofi tele, ase Allahu oba
Pe kama gbagbe alaini ati awon atoroje
Eni nyo zakat ari esan gba, dajudaju

Wa atuu zakawta wa-aqridu llaha qoridon hassanan
Wama tuqodimuu, li-anfusikum min khayrin
Tejduhu hinda llaahi huwa khayran wa a-azima ajran

Ha!
Ise're mare ema fiaile emu ni koko, olohun o ni f'eru e sile toje oloore
Ti kii gbagbe alaini atawon atoroje
Bose nyan zaka lonri esan gba, esan nla loje

Mo nyo zakat ninu owo mi, mofi tele, ase Allahu oba
Pe kama gbagbe alaini ati awon atoroje
Eni nyo zakat ari esan gba, dajudaju

Oun l'opo keta, oun l'opo keta ninu isilamu t'olohun wi
Toba nyan zaka ninu owo ma lowo fin mo
Atun je isho lori eru re tobamu nise
Sati ma gbagbe alaini o

Ore koma gbagbe alaini atawon atoroje
Eni nyan zaka ari esan gba dajudaju

Mo nyo zakat ninu owo mi, mofi tele, ase Allahu oba
Pe kama gbagbe alaini ati awon atoroje
Eni nyo zakat ari esan gba, dajudaju

Olowo loje ooooo, ore
Olowo loje, oto oseku koma ranti pe
Toba yo zaka ninu owo re o, oba ore ni

Olola nio otun gbajumo, ninu ola laye
Toba nyo zaka ninu ola e ike nla loje
Sati ma gbagbe alaini, sati ma gbagbe alaini atawon aroroje
Eni nyo zaka ari esan gba, ike nla laje

Mo nyo zakat ninu owo mi, mofi tele, ase Allahu oba
Pe kama gbagbe alaini ati awon atoroje
Eni nyo zakat ari esan gba, dajudaju

Toba yo zaka tofun iyawo e zaka ko loyo
Toba yo zaka tofun iyawo e zaka ko loyo
Bi ko yo zaka to fun mama ati baba ko rara

Omo si mama tabi baba naa s'omo toba bi
Toba yo zaka tofun ébí e, zaka ko loyo
Awon to sunmo ati ara'dugbo, awon lo tosi

Masi yo zaka los'ilu miran afibi toba wa, awon totimo lalaini o
Awon totimo lalaini atawon atoroje
Sewon lanfani kori esan gba lowo oba mimo

Mo nyo zakat ninu owo mi, mofi tele, ase Allahu oba
Pe kama gbagbe alaini ati awon atoroje
Eni nyo zakat ari esan gba, dajudaju

Ewo egba zaka inu owomi niyen lododun
Ewo egba zaka inu owo mi niyen lododun
Iwo gb'ebun yi, zaka ola mi niyen lododun

Toba ti soyen mofe komope zaka ko rara
Toba yo zaka to funyan maje o mo poun loyo fun
Se lasepamo maje ko jona motomoto rara
Sewon lanfani kori esan gba
lowo oba mimo

Mo nyo zakat ninu owo mi, mofi tele, ase Allahu oba
Pe kama gbagbe alaini ati awon atoroje
Eni nyo zakat ari esan gba, dajudaju

Oun t'olohun bere ninu owo e, koju bintin
Unt'olohun bere ninu owo e, koju bintin
Ninu 1 million 25 thousand, loje lodun

Ninu 10million, 250 thousand, lodun loje
zaka yiyo o si fawon talika afeni tolowo
Bieni to lowo to po ni bank lorisirisi

Toje lodun kan tio ba gbowo nbe kole ni lara
Iruwon leni towo won tiwo zaka ni yiyo
Kosha ma gbagbe oo, kosha magbagbe alaini atawon atoroje
Eni yo zaka ari esan gba, nlanla

Mo yo zakat ninu owo mi, mofi tele, ase Allahu oba
Pe kama gbagbe alaini ati awon atoroje
Eni nyo zakat ari esan gba, dajudaju

Boje'le loni toba sije ile lole fi riyo
Boje nkan òsìn bosije motor lole fi riyo
Bose nkan jije, toba sije nkan ogbin ni kofi yo
Sungbon oun todaju koje owo ni zaka ni yiyo

Eni o rowo jeun toba fun lókò kilofe fise, eni o renu bo
Toba fun nile ishoro lofi ba
Iwo ba so dowo kofun kofise nkan tobafe

Shati yo zakaaa, shati yo zaka ninu owo e kofi tele
Ase allahu oba, Mo nyo zakat ninu owo mi
Mofi tele, ase Allahu oba

Kasi ma gbagbe alaini ati awon atoroje
Eni nyo zakat ari esan gba, dajudaju

Mo nyo zakat ninu owo mi, mofi tele, ase Allahu oba
Pe kama gbagbe alaini ati awon atoroje
Eni nyo zakat ari esan gba, dajudaju

L'odun èshí ninu owo e, sho yo?
Ninu owo e, sho yo
L'odun èshí ninu owo e, sho yo?
Idunta ninu owo e, sho yo?
L'odun eni ninu owo e, sho yo?
Ninu ola e, sho yo?
Ninu dukia, sho yo?
Ore ninu owo e, sho yo?

Ore ninu owo e, sho yo?
Mentioning names of big fans
Sho yo?
Written by: Oriyomi Kehinde



Credits
Writer(s): Oriyomi Sanni
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link