Oun Meta

Interlude
T reign on the mix
Loun meta leda nwa o, eda nw'owo eda nw'omo, eda nwa atubotan ire

Oun meta leda nwa o, eda nw'owo eda nw'omo, eda nwa atubotan ire

Igba meta leda nnio
Igba owuro, igba osan, ati àsálé tonje atunbotan eni
Eda nji laye eda nwowo, eda ngbero ati bimo o

Won gbagbe konwa atunbotan ire
Oun meta leda nwa o, eda nw'owo eda nw'omo, eda nwa atubotan ire

Haa
Eniyan tonsare ati lowo, eda kan tonsare ati lola
Eniyan tongbero ati bimo o, towa nkemo lakebaje arami o

Ko k'omo lesin bonse ngbaye
Debi tan o kirun kofi ko won, o dagba o gbo tan ko s'agbara

L'awon omo ba nta ile mo baba lori, béè mani won tun gbemi arawon
Egbo se iyen j'atunbotan ire?

Atunbotan nile aye matun kere, si igba teda ba palemo laye, t'eda ba ba ara e nile ikeyin
Ni sàréè ile ifúnpínpín

Ibi tio s'áyè ati wamo, koni sowo koni s'omo, ile teda ko laye o ni simo
Nkan marun pere ma nan o bere, k'olohun dakun je kale sàséyégé
Maje k'eśu kan o takomi olohun, dakun jen latunbotan ire

Oun meta leda nwa o
Eda nw'owo eda nw'omo
Eda nwa atubotan ire

Nkan marun tiwon o bere: talolohun re tal'ojise? kioesin re nibo l'adojuko?
Man kitaabuka kini tírà?
Tao ba komo lesin Olohun
Nje a fe ko latunbotan're

Oun meta leda nwa o
Eda nw'owo eda nw'omo
Eda nwa atubotan ire

Irawo mi jeko tan titi dale amin
Irawo mi jeko tan titi dale amin
Ebun to funmi oyato si tenikanlan
Osemi lakanda eyan laye timowa, eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe

Irawo mi jeko tan titi dale ami
Ebun to funmi oyato si tenikankan
Osemi lakanda eyan laye timowa
Eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe

Irawo miii

Irawo mi jeko tan titi dale ami
Ebun to funmi oyato si tenikankan
Osemi lakanda eyan laye timowa
Eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe

Mashaallah
Allahumma anfaany bima alamtany, wa alimny ma ynafauny warzuqny
Ilima yanfaunny amina aamin

Sore funmi lori imo to funmi yah Allah
Kosi fiyemi bi yio se tun sanfani funmi
Eyi tofunmi sha lebun timofi nse bebe

Irawo mi jeko tan titi dale ami
Ebun to funmi oyato si tenikankan
Osemi lakanda eyan laye timowa
Eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe

Allah
To be talented lowo olohun loti nwa, ebun mani latorun ki eda towaye
Ale kose carpenter abi ka kose fashion
Mechanical engineer pelu electrician

Ale fe je sailor fun oko oju omi
Ale fe di pilot awako ofurufu o
Kosenikan laye naa tole ko ise orin
Af'eni olohun bafun lebun tofe mo bi yiose lo

Yio mase elegbe leyin toba ya a daduro
Orin to funmi sha lebun timofi nse bebe

Irawo mi jeko tan titi dale ami
Ebun to funmi oyato si tenikankan
Osemi lakanda eyan laye timowa
Eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe

Ise owo mi koma dami láàmu allah, masemi nise lari o tio ma r'owo yo
Masemi lalasedanu tio ni akojo
Masemi lolokiki kan tio wulo fun ebi fara

Gbemi lati superstar kin tun wadi mega
Won lokiki p'ona meji kosetemi nire
Kon tarami rise owo e konfi iru e toro, Ebun to funmio
Ebun to funmi yah robbi kotomi se bebe

Irawo mi jeko tan titi dale ami
Ebun to funmi oyato si tenikankan
Osemi lakanda eyan laye timowa
Eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe

Semi loore ooo
Semi loore tikoni yi sibanuje
Awon omo mi, sewon ni alalubarika, Awon to j'ako, mase je kiwon di ipata
Awon to je abo, konma ma gbe igba iranu

K'obami o sewon lelesin kiwon ma sesin rara
Sewon lologo kawon omo mi mama ya agan
Awa ti abiwon konma riwa ribanuje
Kodawa lola yah robbi kotowa sebebe

Irawo mi jeko tan titi dale ami
Ebun to funmi oyato si tenikankan
Osemi lakanda eyan laye timowa
Eyi to funmi sha lebun timofi nse bebe

O to lope taloni koto lope?
Oba to ponmile pelu ebun mi o tope
Ko yomi seyin lawujo o, ope loye

O to lope taloni koto lope?
Oba to ponmile pelu ebun mi o tope
Ko yomi seyin lawujo o, ope loye

Oke aimoye loti file sasobora tiwon tiku ao fi yowon, ope ni emi finda
Emi o runpa kilemi o ni dupe fun o
Mio waye asan kilemi oni maayo si?

Alhamdulillahi mo r'ope yen da
Oba to ponmile pelu ebun mi o tope
Ko yomi seyin lawujo ope loye

O to lope taloni koto lope?
Oba to ponmile pelu ebun mi o tope
Ko yomi seyin lawujo o, ope loye

Abdul lateef kehinde emi rope da o
Wallahi, mo moore olohun lemi finso
Dupe eyi kotun gbamiran lolohun wi
Atipe ilopo ilopo lore naa a tunje
Oremi dupe maso pe kotope rara o

Boselewu kori laye iru e lawon kan nwa
Oba lo pon e le koje ko toshi o dupe
Ma f'ope sile laida ope loye

O to lope taloni koto lope?
Oba to ponmile pelu ebun mi o tope
Ko yomi seyin lawujo o, ope loye

Igba aini won niyen o lo titi, toripe
Leyin òdá ojo a ro toba ya
Oun tenikan nbinu o wipe o kere
Oun mani enikan ri, tondupe adamojumo

Ha
Ore olohun lorimi o kere rara o
Aanu e layemi o kèrémí ko o
Ko famiseyin lawujo o, ope loye

O to lope taloni koto lope?
Oba to ponmile pelu ebun mi o tope
Ko yomi seyin lawujo o, ope loye

Allah
Maje kin nwaye inira adaniwaye o
Maje kin nwaye inira, adanwaye o
Igbesi aye irorun, ni kin nma gbe
Isemi ayemi ko tutu minimini
Bi t'odèé aramide mi ganiya

Maje kin nwaye inira adaniwaye o
Maje kin nwaye inira, adanwaye o
Igbesi aye irorun, ni kin nma gbe
Isemi ayemi ko tutu minimini
Bi t'odèé aramide mi ganiya

Maje kin nwaye inira adaniwaye o
Igbesi aye irorun, ni kin nma gbe
Isemi ayemi ko tutu minimini
Bi t'odèé aramide mi ganiya

Maje kin nwaye inira adaniwaye o, igbesi aye irorun, ni kin nma gbe
Isemi ayemi ko tutu minimini, bi t'odèé aramide mi ganiya

Dida oruko alatileyin mi
Alhaja ganeeyat aramide biola alaka, tesiwaju

Maje kin nwaye inira adaniwaye o
Maje kin nwaye inira, adanwaye o
Igbesi aye irorun, ni kin nma gbe
Isemi ayemi ko tutu minimini
Bi t'odèé aramide mi ganiya

Dida oruko alatileyin mi
Alhaja ganeeyat aramide biola alaka tesiwaju

Maje kin nwaye inira adaniwaye o
Maje kin nwaye inira, adanwaye o
Igbesi aye irorun, ni kin nma gbe
Isemi ayemi ko tutu minimini
Bi t'odèé aramide mi ganiya

Dida oruko alatileyin mi
Alhaja ganeeyat aramide biola alaka, tesiwaju

Maje kin nwaye inira adaniwaye o
Maje kin nwaye inira, adanwaye o
Igbesi aye irorun, ni kin nma gbe
Isemi ayemi ko tutu minimini
Bi t'odèé aramide mi ganiya

Eni t'olohun, ba s'eda e l'oloore
Awa t'olohun ba ran iru eda bayen si
Kasaponle e, b'obaseto ati b'oseye
Kase emi imoore, katun gbore alekun laye

Eni t'olohun, ba s'eda e l'oloore
Awa t'olohun ba ran iru eda bayen si
Kasaponle e, b'obaseto ati b'oseye
Kase emi imoore, katun gbore alekun laye

Dida oruko oloore mi
Alhaji wasiu olaide alaka, tesiwaju

Eni t'olohun, ba s'eda e l'oloore
Awa t'olohun ba ran iru eda bayen si
Kasaponle e, b'obaseto ati b'oseye
Kase emi imoore, katun gbore alekun laye

Dida oruko oloore mi
Alhaji wasiu olaide alaka, tesiwaju

Eni t'olohun, ba s'eda e l'oloore, awa t'olohun ba ran iru eda bayen si, kasaponle e
B'obaseto ati b'oseye
Kase emi imoore, katun gbore alekun laye

Dida oruko oloore mi
Alhaji wasiu olaide alaka, tesiwaju

Eni t'olohun, ba s'eda e l'oloore
Awa t'olohun ba ran iru eda bayen si
Kasaponle e, b'obaseto ati b'oseye
Kase emi imoore, katun gbore alekun laye

Alhaji latifu kokonbilo, billooo
Àjéyè kokonbilo, bilooo
Adigun ti shaproper tipe
Awon ota e wa nsare lasan

Alhaji latifu kokonbilo, billooo
Àjéyè kokonbilo, bilooo
Adigun ti shaproper tipe
Awon ota e wa nsare lasan

Dida oruko alatileyin mi
Alhaji abdul lateef adigun kokonbilo tesiwaju

Alhaji latifu kokonbilo, billooo
Àjéyè kokonbilo, bilooo
Adigun ti shaproper tipe
Awon ota e wa nsare lasan

Dida oruko alatileyin mi
Alhaji abdul lateef adigun kokonbilo tesiwaju

Pataki toje, seleyi o to l'apere ni?
Awon ìgbà tolo, tooti lo, lofin nrope da
Awon eyan tomo, totimo
Lofin nmo koko
Pataki toje seleyi o to lapere ni

Dida oruko alatileyin mi
Alhaji abdul lateef adigun kokonbilo tesiwaju

Pataki toje, seleyi o to l'apere ni?
Awon ìgbà tolo, tooti lo, lofin nrope da
Awon eyan tomo, totimo
Lofin nmo koko
Pataki toje seleyi o to lapere ni

Dida oruko alatileyin mi
Alhaji abdul lateef adigun kokonbilo tesiwaju

Pataki toje, seleyi o to l'apere ni?
Awon ìgbà tolo, tooti lo, lofin nrope da
Awon eyan tomo, totimo
Lofin nmo koko
Pataki toje seleyi o to lapere ni

Igba t'olohun da e n'ikoko o bo sinu
Osu mesan ninu oyun o wa saye
Ojo ti abi e ta lolemo, oun tofe je
Male gbagbe l'ojo ti awi

Igba t'olohun da e n'ikoko o bo sinu
Osu mesan ninu oyun o wa saye
Ojo ti abi e ta lolemo, oun tofe je
Male gbagbe l'ojo ti awi

Dida oruko alatileyin mi
Alhaji abdul Kabeer checkmate tesiwaju

Igba t'olohun da e n'ikoko o bo sinu
Osu mesan ninu oyun o wa saye
Ojo ti abi e ta lolemo, oun tofe je
Male gbagbe l'ojo ti awi

Dida oruko alatileyin mi
Alhaji abdul Kabeer checkmate, tesiwaju

Igba t'olohun da e n'ikoko o bo sinu
Osu mesan ninu oyun o wa saye
Ojo ti abi e ta lolemo, oun tofe je
Male gbagbe l'ojo ti awi

Dida oruko alatileyin mi
Alhaji abdul Kabeer checkmate, tesiwaju

Igba t'olohun da e n'ikoko o bo sinu
Osu mesan ninu oyun o wa saye
Ojo ti abi e ta lolemo, oun tofe je
Male gbagbe l'ojo ti awi

Aponle hajji rashidi ninmase
Gbogbo igba tinba ranti e ninma fun
Opolopo adua naa ao mase
Emi gigun fun rashidi agunwa

Dida oruko alatileyin mi
Alhaji abdul rasheed agunwa tesiwaju

Aponle hajji rashidi ninmase
Gbogbo igba tinba ranti e ninma fun
Opolopo adua naa ao mase
Emi gigun fun rashidi agunwa

Dida oruko alatileyin mi
Alhaji abdul rasheed agunwa, tesiwaju

Aponle hajji rashidi ninmase
Gbogbo igba tinba ranti e ninma fun
Opolopo adua naa ao mase
Emi gigun fun rashidi agunwa

Oore ajeunjetan
Konimo niwo nikan
Yio je tomotomo
Tomotomo t'aromodomo
Ati aromodomo omo
Tebi tara oore ni

Oore ajeunjetan
Konimo niwo nikan
Yio je tomotomo
Tomotomo t'aromodomo
Ati aromodomo omo
Tebi tara oore ni

Dida oruko alatileyin mi
Alhaji abdul rasheed agunwa, tesiwaju

Oore ajeunjetan
Konimo niwo nikan
Yio je tomotomo
Tomotomo t'aromodomo
Ati aromodomo omo
Tebi tara oore ni

Oore ajeunjetan
Konimo niwo nikan
Yio je tomotomo
Tomotomo t'aromodomo
Ati aromodomo omo
Tebi tara oore ni

Dida oruko alatileyin mi
Alhaji abdul rasheed agunwa, tesiwaju

Oore ajeunjetan
Fun tebi tara gbogbo wa

Oore ajeunjetan
Konimo niwo nikan
Yio je tomotomo
Tomotomo t'aromodomo
Ati aromodomo omo
Tebi tara oore ni

Ebami sope kiku mapa madina, amin, K'iku mapa madina
K'arun kankan
Mase alhaja jennifer
Ifaseyin koma yale re lailai

K'iku mapa madina
K'arun kankan
Mase alhaja jennifer
Ifaseyin koma yale re lailai

Dida oruko alatileyin mi
Alhaja medinat Jennifer, tesiwaju

K'iku mapa madina
K'arun kankan
Mase alhaja jennifer
Ifaseyin koma yale re lailai

Dida oruko alatileyin mi
Alhaja medinat Jennifer, tesiwaju

K'iku mapa madina
K'arun kankan
Mase alhaja jennifer
Ifaseyin koma yale re lailai

Dida oruko alatileyin mi
Alhaja medinat Jennifer, tesiwaju

K'iku mapa madina
K'arun kankan
Mase alhaja jennifer
Ifaseyin koma yale re lailai

Olohun lose e l'ogo ogun ko
Konma tópínpín
Oba loda e lola esu ko
Konma wa kiri o
Madina oni s'alai magoke jubi toga de
Iwa jennifer to niwa tale ma kose

Olohun lose e l'ogo ogun ko
Konma tópínpín
Oba loda e lola esu ko
Konma wa kiri o
Madina oni s'alai magoke jubi toga de
Iwa jennifer to niwa tale ma kose

Dida oruko alatileyin mi
Alhaja medinat Jennifer, tesiwaju

Olohun lose e l'ogo ogun ko
Konma tópínpín
Oba loda e lola esu ko
Konma wa kiri o
Madina oni s'alai magoke jubi toga de
Iwa jennifer to niwa tale ma kose

Dida oruko alatileyin mi
Alhaja medinat Jennifer, tesiwaju

Olohun lose e l'ogo ogun ko
Konma tópínpín
Oba loda e lola esu ko
Konma wa kiri o
Madina oni s'alai magoke jubi toga de
Iwa jennifer to niwa tale ma kose

Malaika kan ni dende f'awon tonjise fun
Transformer ni dende f'awon to ntanna fun
Ibraheem dende ooyii
Omo égúngbóùn dende ooyi
Bosense nio ma selo

Dida oruko alatileyin
Alhaji Ibraheem dende tesiwaju

Ibraheem dende ooyii
Omo égúngbóùn dende ooyi
Bosense nio ma selo

Dida oruko alatileyin
Alhaji Ibraheem dende tesiwaju

Transformer ni dende f'awon to
Ibraheem dende ooyii
Omo égúngbóùn dende ooyi
Bosense nio ma selo

Mashaallah
B'oju o jola ipénpéjú, naam
Bi iwin ma sha laoba ri, naam
Biose ejika togbe aso wa ro, beeni o
Yègèrè laso o bari, lorun wa o e
Bioba se p'awon alaanu t'olohun fi timi
Ota o bati kun fun yeye wa

B'oju o jola ipénpéjú
Bi iwin ma sha laoba ri
Biose ejika togbe aso wa ro
Yègèrè laso o bari
Bioba se p'awon alaanu t'olohun fi tiwa
Ota o bati kun fun yeye wa

Dida oruko alatileyin
Alhaji saheed babatunde (Mr sport) tesiwaju

B'oju o jola ipénpéjú
Bi iwin ma sha laoba ri
Biose ejika togbe aso wa ro
Yègèrè laso o bari
Bioba se p'awon alaanu t'olohun fi tiwa
Ota o bati kun fun yeye wa

Dida oruko alatileyin
Alhaji saheed babatunde mr sport tesiwaju

B'oju o jola ipénpéjú
Bi iwin ma sha laoba ri
Biose ejika togbe aso wa ro
Yègèrè laso o bari
Bioba se p'awon alaanu t'olohun fi tiwa
Ota o bati kun fun yeye wa

Dida oruko alatileyin
Alhaji saheed babatunde mr sport tesiwaju

B'oju o jola ipénpéjú
Bi iwin ma sha laoba ri
Biose ejika togbe aso wa ro
Yègèrè laso o bari
Bioba se p'awon alaanu t'olohun fi tiwa
Ota o bati kun fun yeye wa



Credits
Writer(s): Oriyomi Sanni
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link