Aropin

Laaa ta-akhiranna unaasan fi makhasomatiy
Innal ba-uudontan tudiniy, mukhlatal hasadiy
Inna ba-uudontan tudiniy, mukhlatal hasadiy

Oni l'eda ri ao mola
Oni l'eda ri ao molaaaa
Maso p'enikan wa tio lega o
Eni leda ri ao mola
Maf'oju kere omo eyan kan
Oni leda ri ao mola

Olohun lo niyi at'ola o, omo eyan lo l'aropin
Awon ton rope óòlela, won o pada wa ba e f'owo
Awon tonso p'óòlela, óópádà ma pada ma bowon

Olohun lo niyi at'ola o, omo eyan lo l'aropin
Awon ton rope óòlela, won o pada wa ba e f'owo
Awon tonso p'óòlela, óópádà ma pada ma bowon

Olohun lo niyi at'ola ooo
Ọmọ eyan lo l'aropin
Olohun lo niyi at'ola o, omo eyan lo l'aropin
Awon ton rope óòlela, won o pada wa ba e f'owo
Awon tonso p'óòlela, óópádà ma pada ma bowon

Olohun lo niyi at'ola o, omo eyan lo l'aropin
Awon ton rope óòlela, won o pada wa ba e f'owo
Awon tonso p'óòlela, óópádà ma pada ma bowon

MashaaAllah!

Aronipin o ma m'ojo ola nio, eni lonwo fi dajo,
Kogbagbo pe oni le koro, ola eda o pada dun o
Awon eda aronipin, eni nonfi nshiro olaa

Oju pe seleyi le la,
won ti fi womi ninu aye ri, won tun fin womi lowolowo
Seb'olohun l'opabida ton fagbara e sobi dire
Bami tun aye mise ooo, Bami tun aye mise o oo,
Bami tun ayemi se o
K'oju o le t'awon aronipin

Olohun lo niyi at'ola o, omo eyan lo l'aropin
Awon ton rope óòlela, won o pada wa ba e f'owo
Awon tonso p'óòlela, óópádà ma pada ma bowon

Oju ogbe nibi t'owo o leto, ni k'awon eyan ton ronipin
Ko loje ninu ebi eni ni, ole s'awon tobi e saye
Toba lo j'awon nonro e pin, ton tun pada so to tungbo

Yio dunni j'oju egba, a dunyan ju'gba egba lo
B'eyan ba sope oolela ma rope o ma shile aye wa
F'adua fi w'ona abayo, yio pada daa fun e

Olohun lo niyi at'ola o, omo eyan lo l'aropin
Awon ton rope óòlela, won o pada wa ba e f'owo
Awon tonso p'óòlela, óópádà ma pada ma bowon

Ooh!
Ifúnpínpín oga lori omose o, t'omose ba njiya ekose
Bi k'omose o sasise lori ise k'oga wa sope
Mio rope o lefi iseyi jeun, ko f'eti gboro ibanuje

A le l'ara eko towa koni pe iyen o masi lara
aropin, ewo ni t'ore s'ore o, ore tonmu ore e leru
Toriipe koto rije, koto le rina owo reni o, tobani gbami oremi

Moma fe ko ranmilowo o f'owo,
wa lo gbo kolo ba e foso o, kotun ba e fo motor komo
Ise egbin leyi to ran o

Oti d'aropin Baba aropin
Aropin ni
Oti rope toba dola o, kole dolola iyen o ma da

Ore ma f'ore e śofa o le pada da fun laye
Tikoba sewipe o nropin, śowa le mu bi eru ni

Olohun lo niyi at'ola o, omo eyan lo l'aropin
Awon ton rope óòlela, won o pada wa ba e f'owo
Awon tonso p'óòlela, óópádà ma pada ma bowon

Béè!
Eni a r'opin toba binu to para e kole r'ore olaaa
Olohun lo meto tofe o, f'omo eyan ton ropin tan
B'odi lola to pada wa d'eyan ton nwari fun

Anfani ti yiose ma nipe o, yio je k'awon eda ton nronipin
Kon a pada ri pe ko dara, teniyan ba nro'rawon pin
Eni ton ropin topada la ooo

Toba je p'oti pokun so tabo pada ti
gbe nkan je se yio pada wari boseri?
Iwo ma ro poolela yio pada s'ofe gbo
L'oju awon ton nro e pin, opada marise

Olohun lo niyi at'ola o, omo eyan lo l'aropin
Awon ton rope óòlela, won o pada wa ba e f'owo
Awon tonso p'óòlela, óópádà ma pada ma bowon

MashaaAllah
Won ma ro muhanmma pin won le ni makkah nibi atibi
Loba gba madina lo, l'annabi ba d'ogo agbaye
Won pada jèrãn e ni, nilu makkah nibi tonti le

Won tiro mandela pin b'oselo s'ewon
ijangbara, o pada d'olori ori ede titi t'ofi ku
Ogun aropin ninu ayemi
Aropin ninu ayemi
Jeko ditan kopada pin, gbogbo awon ton nromi pin

Kin funwon l'owo ko d'ajopin,
orimi ton rope o lela jeko pada d'ori olola
Igbiyanju losan loru, yah robbi fi kemi

Olohun lo niyi at'ola o, omo eyan lo l'aropin
Awon ton rope óòlela, won o pada wa ba e f'owo
Awon tonso p'óòlela, óópádà ma pada ma bowon

Omo eda e f'arayin bale
E f'arayin bale f'oluwa o
Oba to iseto, oba to nseto atije atimu

E f'arayin bale
E f'arayin bale f'oluwa o
Oba to nseto, oba to nseto atije atimu

Oriyomi mio wa're lawati, mo f'arabale f'oluwa ni o e
Ko s'ore funmi ti, tor'alaseti ko l'oluwa mi o a

Kotun jen j'alasepati, aseyori l'oba fi soromi o o
Ogo tonyo kele, kele, kelekele
Ogo tonyo kele, yio pada wa debi tonlo naa ni

Koje ko sare ju, koma pada wa lo ku sona ni o e
O tin sunmo'be, maje kopada lo seyin mo Allah
B'ose soromiii
Allah bose soromi
Opàpà jasope funmi naa ni

Mo f'arami bale o
Mo f'arami bale f'oluwa o
Oba to nseto
Oba to nseto atije atimu

E f'arayin bale
E f'arayin bale f'oluwa o
Oba to nseto, oba to nseto atije atimu

Akanni moranti enikan, to tori iyi ile ana o e,
ode tonse nile ana, oti ra agbo kan ewure kan
Otun funwon ni 200 thousand pe won lefe ra nkãn

L'enikan ba wole lojiji,
2 million lo ko f'awon ana, malu meta ati apo iresi pelu elubo o
Iseju kan sikeji, oti bere sini ronu ona
Lati lowo lojiji, wip'abuku loje f'oun o o, loba gb'oko ole lo

O lo jale o rowo ji o e, lojo party l'olopa bade soju agbo éèrí
Won ko śékéśekè o, won ma ko śékéśekè o
Won fi si lese pelu owo o a, e w'aye oponu

Ko f'arabale fun kadara o e
E je f'arayinbale o
F'oba to nseto atije atimu

E f'arayin bale
E f'arayin bale f'oluwa o
Oba to nseto, oba to nseto atije atimu

Maashaallah!
Sobru li insani, ala-l adzaa, sababu s-sa-aadati
S'eni ò r'owo na,
s'olese tose Olohun nio e, awon ton nrina, mimoose ko olohun naa ni

Oba to nshola feni towu kofun lola e ni
Idi kan sikeji, tio fi tete shola fun e, o le fe da duro d'igba
Atasiko toma niyi ni

Awon kan toti lola ri
Owo tonfi logba o to ra shoe re
Eni ba nkanju, ton w'ona ola losibi tio da
Toba r'owo yen tan, boselewu kola yen naa to

Laye awon tola, owo yen o mani toora tyre kan
E je f'arayin bale o, e f'arayin bale, e f'arayin bale f'oluwa o
Oba to nseto, oba to nseto atije atimu

E f'arayin bale
E f'arayin bale f'oluwa o
Oba to nseto, oba to nseto atije atimu

Ma f'ojukokoro o, simi loju mio kuku ni tele naa
Ashiri nmofe, tio bomi konma ridi mi

Áayó okan, tio ni je nronu koja aye o
At'itelorun, Kinma le ranju no nkan oni nkan
Ifokanbale, kinle f'ayo pade olami, oti soriire ri
O matisoriire ti, kosemo mafi kangun soromi

Atelewo eyi o, mofi s'aya mogbe totun naa le, irun lo njebe
Kinma se f'èsìn sile laise
Moti f'arabale o, f'oba to lana to loni o a
Oba to lola, eni to nseto atije atimu

E f'arayin bale
E f'arayin bale f'oluwa o
Oba to nseto, oba to nseto atije atimu

Oun nio seto, oun nio seto atije atimu
Oba to nseto, oba to nseto atije atimu

Oun nio seto
Oun nio seto atina atilo
Oba to nseto, oba to nseto atije atimu

Credits
Writer(s): Oriyomi Sanni
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link