Idera

Olohun bawa f'idunnu lebanuje lo Allah
Idera to nyo, inira funni laye o
Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o
Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo

B'awa f'idunnu lebanuje lo Allah
Idera to nyo, inira funni laye o
Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o
Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo

Yah robbi bawa f'idunnu lebanuje lo Allaaah
Bawa f'dunnu lebanuje lo Allah
Idera to nyo, inira funni laye o
Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o
Lawa se ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo

B'awa is f'idunnu lebanuje lo Allah
Idera to nyo, inira funni laye o
Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o
Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo

Ha, iyawo enikan lo bimo loba fi bi ibeta o
Oko iyawo gbo o, pe iyawo bimo tuntun
Seri boko segbo lova fijo be erebe
Sungbon nigba togbo pe meta lomo ko jomo

Oko o de hospital toko fi salo
O nibo lowo wa, toun o fi gbomo kosi o
Oun ayo lomo tuntun sungbon kini yio se o?

Kowu ko salo koma sowo ni Allah
Gbogbo awon towa ninu condition pe sowo
Dakun bawon fowo le oshi danu
Tori wonti ntoro idera pe kose o
Bawon tete se won e lelomiran, ju'wo lo

B'awa is f'idunnu lebanuje lo Allah
Idera to nyo, inira funni laye o
Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o
Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo

Awon agan won nfara ro nkan ko kere o
Igba tonsese fe se lebi ko mora won re o
L'odun kan ikeji tofi podun merin ko bimo

Ati iya ati baba oko ton feran e rio
Ati iya ti baba oko tonti so po nice
Won lo kan njaje sanra ni ko f'orun bimo
Won wa sofun iyawo pe taba pada wa ka b'omo

Afairi omo lilo loo lo o
Niya oko ati baba oko ba pada de won leju
B'iyawo se kunle toku ko kiwon o

O se bi eni tofe bì sare wo yara lo,
awon ro poti loyun ni, niwon ba ndunnu o
Èrù won lonba o lose dogbon bi po loyun
Iyawo naa o ma mo, p'oyun tiwa lara o

Leyin osu mesan o d'olomo laye o
E w'ore iyanu nigba tio lero o
Gbogbo awon agan ton nireti fun omo
Allahu wahidu tete bawon se o
Wa s'ore iyanu won o lelomiran juwo lo

B'awa is f'idunnu lebanuje lo Allah
Idera to nyo, inira funni laye o
Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o
Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo

MashaaAllah
Ase at'abara to to'le aye gbe o, igbesi aye irorun ati alafia o
Ati iranlowo ti ko latako ninu o
Aanu tio se dede ojo ori ni mo toro
Masaise funmi sebiwo lolase re lowo

Idera tonle, oshi wogbo lo nmofe o
Bami tete se mio lelomiran juwo nikan

B'awa is f'idunnu lebanuje lo Allah
Idera to nyo, inira funni laye o
Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o
Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo

Gbogbo ota tiwon tin nfiwa se yeye o
Tiwon ma ndarin ayo lori ibanuje eniyan
Ilekun ton ti se ton tiro poti o, Olohun bawa si kosi sile fun ire ayo

Awon aye okunkun to njewa niya o
Bawa tan imole, ko dayo funwa la toro
Awa tun nbere aanu pekose
Bawa tetese ao lelomiran juwo allah

B'awa is f'idunnu lebanuje lo Allah
Idera to nyo, inira funni laye o
Itura tonle, arun wo igbo lo lafe o
Lawa fi ntoro idera pe kose o, ba wa tete se ao lelomiran juwo lo

Kini mofe kini iwo naa nfe o
Ideraaa
Kini mofe kini iwo naa nfe o
Ideraaa
T'olohun ba s'owo kama fi wo arun
Ideraa

T'olohun ba sola, koma d'ibaje o
Ideraa

Gbogbo dukia kama gbeta nio
Ideraa
Awon omo tabi kiwon ma yanku
Ideraa
Kise ma dise kama r'oja ta o
Ideraa
Kama se ribanuje lojo nkan eye wa, ideraa
Kini mofe kini iwo naa nfe kowi na



Credits
Writer(s): Oriyomi Sanni
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link