Oun Gbogbo

Ilu
Qodiru ala ma yashau
Oluwa kosiun ti olese
Qodiru ala ma yashau
Oluwa kosiun ti olese

Qodiru ala ma yashau
Oluwa kosiun ti olese
Qodiru ala ma yashau
Oluwa kosiun ti olese

Isorokisoro teniyan ba ni
Tigbogbo aye tiro pe kole yanju mo
Enikan soso tole layan nbe
Ladani magbagbe onise iyanu

Qodiru ala ma yashau
Oluwa kosiun ti olese

Pharaoh le musa debi okun pupa
Otiro pe kosibi tole gba mo nbe
Musa fopa lana sara okun pupa
Abe o roluwa onise iyanu

Qodiru ala ma yashau
Oluwa kosiun ti olese

MashaaAllah

Zakariyah pelu iyawo re pogorun odun
Olohun o funwon lomo wo ri rara
Igba tolohun loya bon osele semo to
Won kan fara kanra, won bimo iyanu

Qodiru ala ma yashau
Oluwa kosiun ti olese

Olohun kilolese?
Oun gbogbo lolese
Ani kilolese?
Oun gbogbo lolese
Olohun aso
Oun gbogbo lolese
Asekan makukan
Oun gbogbo lolese
Oba tio laseti
Oun gbogbo lolese
Oun t'aye lotiku
Iwo nikan loleji
Oun gbogbo lolese
Ona tonso poti di
Oun gbogbo lolese
Oti gbabomiran shi
Oun gbogbo lolese

Awon okunkun toti shu
Oun gbogbo lolese
Iwo ti tan imole si
Oun gbogbo lolese
Abosi tan bosi o
Oun gbogbo lolese
Otilo f'ashiri tu
Oun gbogbo lolese

Oba okan Allahu
La ilaha illa llah
Allahu
La ilaha illa llah
Allaaaaaah
La ilaha illa llah
Allaaaaaaaaah
La ilaha illa llah
La ilaha illa llah
La ilaha illa llah
La ilaha illa llah
La ilaha illa llah
La ilaha illa llah
La ilaha illa llah
La ilaha illa llah



Credits
Writer(s): Oriyomi Kehinde
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link