Ìgbà

Ilu
Shocker lose beat
MashaaAllah
Ma faroyaro
Ore malo faroyaro
Ma faroyaro
Ore malo faroyaro
Gbogbo eni tagbe leyin
Ma mako lo foro sinu
Gbogbo eni tagbe leyin
Ma mako lo foro sinu

Awon kan ma nfeyin siwa
Sungbon tonma ntuna loju
Awon kan ma nfeyin siwa
Sungbon tonma ntuna loju

Control your feelings over some matter
Some people wanted to be supportive
But you were thinking that they don't wanna support you, but they do
Awon kan fese sungbon sha
Kogbe igbese ma nonfe
Awon tiwon pada lona
Tiwon paa-da
Ton seripada po jin
Tonseri paa-da
Gbogbo won loda igba ni
Gbogbo won loda asiko ni
Gbogbo won loda igba ni
Gbogbo won loda asiko ni

Awon tiwon pada lona
Tiwon paa-da
Ton seripada po jin
Tonseri paa-da
Gbogbo won loda igba ni
Gbogbo won loda asiko ni
Gbogbo won loda igba ni
Gbogbo won loda asiko ni

Awon tan o kamikun nigbakan
Ti nfimi yangan loju ore won
Olowo tio sebi porimi, lojumi nigbayen odaju ni

Sungbon nisin ati jowa nah
Won tin npemi kinwa gba o
Lasiko yi won tun tinposi, kontun ma posi latun fe e o

Gbogbo eni tagbe leyin
Ma mako lo foro sinu
Gbogbo eni tagbe leyin
Ma mako lo foro sinu
Awon kan ma nfeyin siwa
Sungbon tonma ntuna loju
Awon kan ma nfeyin siwa
Sungbon tonma ntuna loju

Awon tiwon pada lona
Tiwon paa-da
Ton seripada po jin
Tonseri paa-da
Gbogbo won loda igba ni
Gbogbo won loda asiko ni
Gbogbo won loda igba ni
Gbogbo won loda asiko ni

Awon tiwon pada lona
Tiwon paa-da
Ton seripada po jin
Tonseri paa-da
Gbogbo won loda igba ni
Gbogbo won loda asiko ni
Gbogbo won loda igba ni
Gbogbo won loda asiko ni

Ilu

Awon tiwon pada lona
Tiwon paa-da
Ton seripada po jin
Tonseri paa-da

Gbogbo won loda igba ni
Gbogbo won loda asiko ni

Gbogbo won loda igba ni
Gbogbo won loda asiko ni



Credits
Writer(s): Oriyomi Kehinde
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link