Ogbon

Jerryson production
Ma f'ogbon wonmi Allah
Ere aye o to ka r'ogbon
Fi rigba lo dale
Ogbon ga o ma j'agbara lo

Ma f'ogbon wonmi Allah
Ere aye o to ka r'ogbon
Fi rigba lo dale
Ogbon ga o ma j'agbara lo

Jalla jalaaluhu Allah
Oba ogbon tikiise poju ruju
Yuhty li hikmata ma yasha
Waman yuhtal hikmata faqod uhtiya khayran kethseeran

Oba ogbon to npin eda logbon, o funmi niwon temi nlo
Tio je nte logba pelu awujo

Ogbon t'awon aye nko
Ninu orin tanko emi ko
Olohun lopin iyen s'odomi, modupe to kami mo
Awon eyan t'araye njoko de
Pe b'oriyomi ò dé aoti lelo
Iyi da o j'abùkù lo o jare

Ma f'ogbon wonmi Allah
Ere aye o to ka r'ogbon
Fi rigba lo dale
Ogbon ga o ma j'agbara lo

Mase je kojemi nikan, f'oriire pelu órò aye
Matori adua mi naa, kowa fise pàsípàrò ikan
Funmi ko f'omo iyami naa
Kenikan ma woju enikan koto rina

Tori ogun ebi ose dajuko, yio j'ogun ukraine lo
Tebi ba bere ilara

Laye je nr'ogbon fiseee
Dakun jen rogbon fise
Kin tun ri suuru fise
Falaroka n'nu ebi ati alagidi

Bosewu kon dogbon to, komiyo ninu ete gbogbo

Ma f'ogbon wonmi Allah
Ere aye o to ka r'ogbon
Fi rigba lo dale
Ogbon ga o ma j'agbara lo

Ilahi bawa f'ayo ropo ibanuje awon tojepe
Awon toye koje ààyò won, won nbawon s'òtá ojumo

Iyawo to nkoju ogun iya oko, seripe isoro loje
Ati iya oko t'iyawo o jeo gbadun omo tobi debi èrè omo

Bawa segun ogun adojule
Awon tonmu iru e niwa
Bawa yiwon lokan pada, ao sha nife ki okun ebi o ja
Irorun da, oma ju inira lo

Ma f'ogbon wonmi Allah
Ere aye o to ka r'ogbon
Fi rigba lo dale
Ogbon ga o ma j'agbara lo

B'isoro bawole to eda, semope ekún loma nmuwa
Ma maje a r'oro ekun mo
Gbogbo adun towole to eda, semope erin loma nbade

Naam
Kadun ma lomo koma dekun, katewo ka fatiha f'owo boju
Aye o ni dawa lokan le fekun, won o nikiwa fun ibanuje

At'ogbon pelu awon ika, konise lewa lori
K'ogbon ga koju ete won lo

Ma f'ogbon wonmi Allah
Ere aye o to ka r'ogbon
Fi rigba lo dale
Ogbon ga o ma j'agbara lo

Ma s'ogbon mi dete (Allah)
Asiso ma fikun (laye-laye)

Mas'agbara d'ole (Allah)
Asise ma fikun (laye-laye)
Ma f'ìmò mi jóbà, Allah
Àmòjù ma fikun, laye laye

Ma s'oruko d'òfó, Allah
Isoro ma fikun, laye laye
K'alafia ma d'arun, Allah
Inira ma fikun, laye laye

K'ewa mi ma baje, Allah
Ijàmbá ma fikun, laye laye
K'aye mi ma daru, Allah
K'alakoba marise, laye laye



Credits
Writer(s): Oriyomi Sanni
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link