Akankatan

Akankatan, oore olohun lemi ntoro
Ajenjetan, ola olohun lemi nfe
K'atigoke, ayemi mase dona inira

Akankatan, oore olohun lemi ntoro
Ajenjetan, ola olohun lemi nfe
K'atigoke, ayemi mase dona inira

Gbese lewu, toma ndabi akisa o
Mi kiise ayamasan, ola Olohun lemi nreti

Ahun nonpemi, koyewon pe mo mofun
Awon muwa muwa
Mo funwon mofi sedupe

Lasikoyi
Mowa nbelohun ilahi
Komaje nmo mo
B'ikoro senri lara temi mo

Akankatan, oore olohun lemi ntoro
Ajenjetan, ola olohun lemi nfe
K'atigoke, ayemi mase dona inira

Setiri oko oro
Tonma nso sawon akobi
Tiko tete la, won o nife fun laponle

Bonpe ipade, ajoro ninu molebi
Won ani kotete de, oro owo dele kori da
Aitete ni, tonfa k'egbon daburo

Atoshi atishe, olohun bawa le pelase
Kolo tefe-tefe, koma wogbo lo nfemo
Allah lana irorun, kire wole kona o shi

Ara towumiiiiiiii
Ara towumi, koje nle raye ati ma da

Akankatan, oore olohun lemi ntoro
Ajenjetan, ola olohun lemi nfe
K'atigoke, ayemi mase dona inira

Allahuma iniy, iniiiy
Allahuma iniy, ahudzu bika mon zawal

Watahawwul, watahawul afiyatik
Wa fajihati, wafajiati niqmatik

Wajaami-i, wajami-i sakhatik
Olohun alanaaa ooo, Olohun alana

Tonitola titi ainipekun
Iwo lolupese, gbogbo nkan tomo eda nfe
Gbagbara womi, jekin ma rona ati ga lo

Akankatan, oore olohun lemi ntoro
Ajenjetan, ola olohun lemi nfe
K'atigoke, ayemi mase dona inira

Ore maase sodaqo
K'olohun leseke fun e kun
Maase saaraa, k'olohun le lae nibi ewu

Eni tio ni lo ntoro je
Kororun keda o bosi igboro
Edakun egbami ntori Olohun

Òpò won nio tun ni rigba
Kaka k'awon kan o funwon lowo
Bi ewure nonma lewon, modupe t'olohun semi ni funni funni
Oremi osi ma tore

Iwo naa se sodaqo
K'olohun leseke fun e kun
Maase saaraa, k'olohun le lae nibi ewu

Ntajo nreti lori ona oore
Adeun tonse funwa
Tati sokale pe taba rigba
Wipe ao rale kama kole lo

Aniyan tipo taa dale
Mu inu enikan dun kojo tope
Konise koniye oma rire gba o
Olohun aseke atore

Oje yaase sodaqo
K'olohun leseke fun e kun
Maase saaraa, k'olohun le lae nibi ewu

Ore maase sodaqo
K'olohun leseke fun e kun
Maase saaraa, k'olohun le lae nibi ewu



Credits
Writer(s): Oriyomi Sanni
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link