MO GBOHUN OLORUN MI

Mo gbohun Ọlọrun mi tó fi mí lọ'kàn balẹ
Oni kín ma mikan pé ohun tí síji bomi
Mo gbohun Ọlọrun mi tó fi mí lọkàn balẹ
Oni kín ma mikan pé ohun tí síji bomi

Let them judge you
Let them misunderstand you
Let them gossip about you
There opinions aren't your problem
You stay kind, committed to love
And free in your authenticity
No matter what they do or say
Don't you dear doubt your worth
Or the beauty of your throat
Just keep shining like you always do

Mo gbohun Ọlọrun mi tó fi mí lọkàn balẹ
Oni kín ma mikan pé ohun tí síji bomi

I will stand firm during my watch
And fix my position over the fortification
To see what might they said to me
And what I might respond to my opponent
And the lord responded to me and said
Write the vision and explain it on tablet

So that he who reads it, may run through it
For as yet the vision is far off
And it will appear in the end
And it will not lie, if it expirences any delay
Wait for it, for it is arriving
And it will arrive
And it will not be hinderd

Mo gbohun Ọlọrun mi tó fi mí lọkàn balẹ
Oni kín ma mikan pé ohun tí síji bomi

And let us not grow we aren't of doing good
But in due season we will reap
If we do not give up
So them as we have opportunity
Let us do good to everyone
And expecially those
Who on our behalf sold the faith

Àdúa nìkan lole m'ènìyàn bori
Ogun ayé gbogbo ati ète ọmọ ẹ'dá
Àdúa nìkan lole m'ènìyàn bori
Ogun ayé gbogbo ati ète ọmọ ẹ'dá ó
Oti siji bomi o, ẹ'ru kan olè bami mo
Ogun ayé gbogbo ati ète ọmọ ẹ'dá

O má gbọ' bí nse wí
Ẹni ọ'wọ' Pastor Tobi ọmọ Adegboyega ó
Aláṣẹ spark nation
Night shift city welfare ni London
Ọkọ Tosin baby, Babe Ifẹ, Baba Joseph
Eyan tèmi olúayé fuji arabambi ọba orin

Àdúa nìkan lole m'ènìyàn bori
Ogun ayé gbogbo ati ète ọmọ ẹ'dá
Àdúa nìkan lole m'ènìyàn bori
Ogun ayé gbogbo ati ète ọmọ ẹ'dá ó
Àdúa nìkan lole m'ènìyàn bori
Ogun ayé gbogbo ati ète ọmọ ẹ'dá



Credits
Writer(s): Olasunkanmi Ayinde Marshal
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link