Jolly Jolly

Mo.
Mo'believe
Óyá jolly jolly mùkeke
Jé ká seré dowó àle se
Mutí mutí kan n kúsóde
Gèrè gèrè, mà á délé mi se
Let us take more time to mùkeke
Óyá jolly jolly mùkeke
Jé ká seré dowó àle se
Mutí mutí kan n kúsóde
Gèrè gèrè, mà á délé mi se
Óyá jolly jolly mùkeke
Jayé, fàájì
Èlè motí, it's on me
Jayé, fàájì o
Èlè motí, it's on me
Da ba da sada piti ti da ba la dabili
Àrà mo dá sé
Òmùtí gbàgbé ìsé sà kèrègbè dorí
Àrà ló dá sé

Mutí mutí kan n kúsóde
Gèrè gèrè, mà á délé mi se
Let us take more time to mùkeke

Óyá jolly jolly mùkeke
Jé ká seré dowó àle se
Mutí mutí kan n kúsóde
Gèrè gèrè, mà á délé mi se
Óyá jolly jolly mùkeke

Là la lé Friday
You go catch me chilling
Drinking my emu
No time for worries my brother
Chilling, drinking my emu
Pòmó tó yita
Ìgbín tó ń sòróró
Pepper soup o
Give me on the low
Drinking my emu
Mutí mutí kan n kúsóde
Gèrè gèrè, mà á délé mi se
Let us take more time to mùkeke

Óyá jolly jolly mùkeke
Jé ká seré dowó àle se
Mutí mutí kan n kúsóde
Gèrè gèrè, mà á délé mi se
Óyá jolly jolly mùkeke

Jayé, fàájì
Èlè motí, it's on me
Jayé, fàájì o
Èlè motí, it's on me
Jayé, fàájì
Èlè motí, it's on me
Jayé, fàájì o
Èlè motí, it's on me



Credits
Writer(s): Mobolaji Oluwabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link