Kabi E O Si Medley: Awa La Ro Jile / Alagbara / Ka Bi E O Si / Emi Yi O Ma Yin O / Ti Nba So Pe / Oga Eme / Yesu Ubangiji

Kaabi e o si eledumare iwo ti o gbe ogo re ka ori awon orun
Oti wa saju aiye ati bi e saaju awon oke
Owo re lofi la orun ja ogo ni fun o ayin o

Eniti o ba ronu jile nikan lo le mo ore olorun (awa alarojile la mope wa)
Eleduwa mowa ki o oba to da mi si ose o (awa alarojile la mope wa)
Openi wa sola o ni ke abo to toju gbogbo aiye o (awa alarojile la mope wa)
Asore ka ni laya mo m'ope mi de o bi ishe mi o (awa alarojile la mope wa)
Ore re koja oye mi kinni nba tun fi fun o na o? (Awa alarojile la mope wa)

Owo agbara ti mo ri ati alayiripo iwo lo l'ogo aiye mi (awa alarojile la mope wa)
Eni to bati ku o kole yi o beeni okuta kogbo do gba ishe mi se o (awa alarojile la mope wa)
Emi alaye okan mo de tara tokan mo gbe osu ba fun o (awa alarojile la mope wa)

Mo ro o titi jile mo pin so na ototomo yin o mo tuntu o ki si (awa alarojile la mope wa)
Abarapa eyin oloruno o dayin pe bo ke le yin tile (awa alarojile la mope wa)
Ba birun ba ronu jile a yin eldeuwa tori awon to wa nile (awa alarojile la mope wa)
Tori ta ba yin a o si yin ko ni ko ma je olorun mo o (awa alarojile la mope wa)
Awa ta wosan ta dariji yin e'ja jo gbe baba ga (awa alarojile la mope wa)
Olorun ajanaku kiki da ope lo ye o baba baba mi (awa dansaki re lawa tari)

Alagbara ni jesu alagbara ni
Alagbara ni jesu alagbara ni
Oba okun soro okun gbo alagbara
O ni pa lori orun ati aiye alagbara ni
Alagbara ni jesu alagbara ni
Alagbara ni jesu alagbara ni
Oba okun soro okun gbo alagbara
O ni pa lori orun ati aiye alagbara ni
A da ni to lokun inu eniyan oba to tobi ni

Ni salom ni ago re wa nla ni isreali
Ongbe ninu orun ati aiye aditu ni
Oni ipa lori oun gbogbo to da alagbara ni
Alagbara ni jesu alagbara ni
Alagbara ni jesu alagbara ni
Oba okun soro okun gbo alagbara
O ni pa lori orun ati aiye alagbara ni

Awon angeli un yin lorun
Ero gbogbo ninu orun iyin o
Oun lo lorun a tobi ju
Won foribale fun oba awon oba
Won wole fun
Awon agbagba origun aiye foribale o
Aro gbogbo l'aiye e yin o
Mimo mimo l'angeli won ko si o
Eni ibeere ni eni opin ni
E wole fun (o ti wa k'aiye to wa)

Ka bi o o si o
Ka bi o o si o
Ka bi o o si
Mo ju ba re oba awon oba
Ka bi o o si o
Ka bi o o si o
Ka bi o o si o
Mo ju ba re oba awon oba

Awa maridi loruke re
Ori ojiri aiye lo joko si o
Eni mo riri re yin o
Ka jo wole fun oluwa awon oluwa
Ka fi iba fun
Eranko inu igbo yin logo
Teja ibu teye oju orun fagbara re han
Omi okun ati iyanrin yin o
Eda e juba re titi lai lo joba
Ti o ni pekun (titi lai lo joba)

Ka bi o o si o
Ka bi o o si o
Ka bi o o si o
Mo ju ba re oba awon oba

Emi yio ma yin o oluwa mi
Un o pokiki ore re o
Emi yio ma yin o oluwa mi
Un o ma gbo ogo re ga o
Emi yio ma yin o oluwa mi
Un o gbo kiki o re re
Ore to se fun mi ko la ka we o
Anu re si mi ko se fi we
Emi yio ma yin o apata igbala mi
Anu re si mi po ju awon orun lo

Emi yio ma yin o oluwa mi
Un o ma gbo ogo re ga o
Emi yio ma yin o oluwa mi
Un o gbo kiki o re re

Tin ba sope olorun o se to
Tin ba sope olorun o se to
Tin ba sope olorun o se to o
A bara mo re je ni mi o
Tin ba sope olorun o se to
Tin ba sope olorun o se to
Tin ba sope olorun o se to o
A bara mo re je ni mi o

Oun lo mu le ju aiye ja
Oun lo yo mi ni gbe kun aiye o
Oun lo sope kin ma rin kin ma yan fanda mi o je so pe o se to
Ibi o ba mi de ninu aiye
Mi o je sope olorun o se o
Ti o ba se olorun ajanaku o
E bi lere ibo ni un ba wa (e bi lere ibo ni mba wa)

Tin ba sope olorun o se to
Tin ba sope olorun o se to
Tin ba sope olorun o se to o
A bara mo re je ni mi o
Tin ba sope olorun o se to
Tin ba sope olorun o se to
Tin ba sope olorun o se to o
A bara mo re je ni mi o

Iyeru yogoma ogeme ogeme o ogeme
Iyeru yogoma ogeme ogeme yeru yo dio ma
Iyeru yogoma ogeme ogeme o ogeme
Iyeru yogoma ogeme ogeme yeru yo dio ma
Iyeru yogoma ogeme ogeme
Iyeru yogoma ogeme ogeme yeru yo dio ma
Iyeru yogoma ogeme ogeme o ogeme
Iyeru yogoma ogeme ogeme yeru yo dio ma



Credits
Writer(s): Tope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link