Mori Iyanu
Eh eh eh, eh eh eh
Ah ah ah, ah ah ah ah
Oh oh oh, oh oh oh oh
Mori iyanu, eh eh, iyanu
Mori iyanu, eh eh, iyanu
Eh eh eh, eh eh eh
Ah ah ah, ah ah ah ah
Oh oh oh, oh oh oh oh
Mori iyanu, eh eh, iyanu
Mori iyanu, eh eh, iyanu
Bawon kan ba Kuse nigba kan laye won
To ba d'olowo, wọn sọ wipe iyanu ni
B'elo miran ba yàgan ri to ba wa d'olomo eh eh
Wọn sope iyanu ni, lootọ ni, iyanu ni
B'oko bá danu to run jege, teni kankan o f'arapa
Eni orí re pe ni'le taropin t'ọlọrun wa gbégbá
Tabi ẹni to gbojo iku to palemo ti o pada wa ku mọ
Gbogbo rẹ loje iyanu, eh eh o, iyanu ni
Eh eh eh, eh eh eh (gbogbo re lo je iyanu)
Ah ah ah, ah ah ah ah (ninu Aye ta wa yi iyanu po repete)
Oh oh oh, oh oh oh oh
Mori iyanu, eh eh, iyanu (mori iyanu, emi ma ri yanu)
Mori iyanu, ah ahh, iyanu
Iyanu to se kenke, o ka mi laya titi
Ilu kekere kan wa won o tọrọ jẹ bẹẹni wọn o la won sagbe
Arabirin kan wa nibe ta jisẹ fún pe o ma bi iyanu
Ẹda eniyan o le ro, pe iyanu le ti bẹ wa o
Okuku sele bè abi iwọ naa, bi o ti le jo iyanu
Sugbon bi ti ṣe jo iyanu to, ọba ilu kan wà kiri
Obwa lati pa tori e o pa ọpọlọpọ ọmọ
Egbo kini ijoloju ki lo fe fi ọmọ talakà se
B'aye se ri niyẹn eni ma ga oju rẹ a ri to (Abi e o ri o)
Eh eh eh, eh eh eh
Ah ah ah, ah ah ah ah (ki lo lowo fe fi ọmọ talakà se o)
Oh oh oh, oh oh oh oh (egbo na)
Mori iyanu, eh eh, iyanu (emi ma ri yanu kan)
Mori iyanu, ah ahh, iyanu
Odagba (iyanu)
Iṣẹ iyanu akọkọ (iyanu)
Ni Canaan ti Galilee (iyanu)
Ọrọ ninu tempili (iyanu)
Oku ọmọ Jairu (iyanu)
Bartelomew afọju nko (iyanu)
Oda eti pada f'eleti (aikaka tan nise iyanu)
Ìyanu tó ga to jo emi loju ju o
Won da baraba sile awọn alaiṣẹ o ma ṣe o
Ikan o ba kan ekunrere ata ti ọsẹ fi bójú
Pari pari re lori igi agbelebu lo ba so p'otan
A ba ori (iyanu)
A ro ni lára lile (iyanu)
Iya eyi gan gan (iyanu)
Abeni l'owe ekun ti (iyanu)
Iyanu wo lo to eyi ka bi eniyan tori ese araye
Iyanu wo lo to yi o ki a so mo nu tori ẹlẹsẹ pataki
M ba je awa lohun se ale se, eje a bi'ra wa
Ka ma dénú ako iṣẹ o Oba wa ni iyanu
Eh eh eh, eh eh eh (ọjọ mi loju ju)
Ah ah ah, ah ah ah ah (mi o le sa kawe rara)
Oh oh oh, oh oh oh oh
Mori iyanu, eh eh, iyanu (ah iyanu to lami lenu sile)
Mori iyanu, ah ahh, iyanu ni
Ko sagbon ko se tutu to kọjá ẹni f'ẹmi rẹ le'lẹ
Ko tún sí ìfẹ atata kan tó dàbí ìfẹ oluwa
Abi eni wa saye lati wa kese ayé gbogbo lọ
Ko tún sí iyanu miran mo, eyi ni yanu
Oku asi sìn, ojijakadi ni saare
O gba Kokoro lọwọ ikú, ọ gbe iku mi ni isegun
Iku oro re da óò, isa oku isegun re da óò
Ora ìyè aráyé ni Igbo ku, ojinde lojo keta (oluwa ji o)
Ojinde, tiye tiye, lojinde, sí ìyè ayérayé, gbogbo ẹni to fẹ iye ko ka lo
Ojinde, tiye tiye, lojinde, sí ìyè ayérayé, gbogbo ẹni tó fẹ iye ko ka lo
Ojinde, tiye tiye, lojinde, sí ìyè ayérayé, gbogbo ẹni to fẹ iye ko ka lo
Ojinde, tiye tiye, lojinde, sí ìyè ayérayé, gbogbo ẹni to fẹ iye ko ka lo
Itan iyanu t'ife nla le yi o
Lato do asèdá, eledua baba wa
Eni to fi ọmọ rẹ ra arayé pada
Agba iyanu tobi iyanu teni yan ri
Iyan iyanu t'ife nla leyi o
Latodo asèdá eledua baba wa
Eni fi ìfẹ hàn wá ti o fẹ ká parun
Agba iyanu to bi iyanu teni yan ri
Itan iyanu t'ife nla leyi
La tọwọ ife eledua baba
Eni gbawa sile to f'ọmọ kan soso sa awotan ẹsẹ wa
Agba iyanu to ni iyanu teni Yan n ri

Credits
Writer(s): Tope Alabi
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
Altri album
- God's Servant at 70
- Unfading Covenant of Baba Abiye, Ede at 80 (feat. Chigozie Wisdom, Lekan Amos, Bukola Bekes, Elijah Akintunde, Prophet Timothy Funso Akande & Prophet Samson Oladeji Akande) - EP
- The Unusual Praise (Live)
- Oluwa Ni: The Spontaneous Worship
- Best of Tope Alabi
- Hymnal vol.1
- Mori Iyanu
- Igbowo Eda
- Funmilayo
- Unless You Bless Me
© 2024 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.