Ayonbo

Oh-oh, eh, ah-eh
O rí pé, ayọ ń bọ l'òwúrọ, eh-eh
(Ice)

Mo r'ọwọ rẹ nílé àyé mí
O rí pé, ayọ ń bọ l'òwúrọ
T'obà r'ọwọ Oluwa nílé àyé rẹ
Ṣa tí mọ wípé, ayọ ń bọ l'òwúrọ, ye o
Ayọ ń bọ wa l'òwúrọ oo, eh
Ayọ ń bọ wa l'òwúrọ, eh
Ẹkùn le pẹ títì d'alẹ, ṣùgbọn, ayọ ń bọ l'òwúrọ

I say, "Joy in the morning"
Joy every day, that's all I see
Oh, eh-eh, Baba God, na Your light dey shine on me like this o
I no know how to thank You, uh-yea, yea-yea

Every day, burst my brain every day, make me want me to dey pray
Na you be my God, yea, Baba oh-ye
Na You dey bless the person wey no get, Bàbá naa ni

Mo r'ọwọ rẹ nílé àyé mí
O rí pé, ayọ ń bọ l'òwúrọ
T'obà r'ọwọ Oluwa nílé àyé rẹ
Ṣa tí mọ wípé, ayọ ń bọ l'òwúrọ, ye o
Ayọ ń bọ wa l'òwúrọ oo, eh (mo ni, "ayọ, ayọ, ayọ")
Ayọ ń bọ wa l'òwúrọ, eh
Ẹkùn le pẹ títì d'alẹ, ṣùgbọn, ayọ ń bọ l'òwúrọ

Hmm, na You be the God promise
Na You be the God of Covenant o
The promise wey You do for my life o, má jẹ ko kọjá mí
Na You, na You o, na only You o
Ìwọ ṣa lo ń ṣọ mi o, iwọ ṣa lo ń ṣe òun gbogbo eh

Burst my brain every day (every day), make me want to dey pray
Na you be my God, yea, Baba oh-ye
Na You dey bless the person wey no get, Baba naa ni

Mo r'ọwọ rẹ nílé àyé mí
O rí pé, ayọ ń bọ l'òwúrọ
T'obà r'ọwọ Oluwa nílé àyé rẹ
Ṣa tí mọ wípé, ayọ ń bọ l'òwúrọ, ye o
Ayọ ń bọ wa l'òwúrọ oo, eh (mo ni, "ayọ, ayọ, ayọ")
Ayọ ń bọ wa l'òwúrọ, eh
Ẹkùn le pẹ títì d'alẹ, ṣùgbọn, ayọ ń bọ l'òwúrọ

Eh-eh-eh-eh, uh-oh (Ice)
Ayọ ń bọ l'òwúrọ
Yea-yea-yea-oh-uh-oh-oh
Ice, ayọ ń bọ l'òwúrọ



Credits
Writer(s): Barry Jhay
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link