Boruko Jesu ti dun to

Boruko Jesu ti dun to
Ogo ni fun Oruko Re
O tan banuje at'ogbe
Ogo ni fun Oruko Re

Ogo foko Re, Ogo foko Re
Ogo foruko Oluwa
Ogo foko Re, Ogo foko Re
Ogo f'oruko Oluwa

O wo okan to gbogbe san
Ogo ni fun Oruko Re
Onje ni f'okan t'ebi npa
Ogo ni fun Oruko Re

Ogo foko Re, Ogo foko Re
Ogo foruko Oluwa
Ogo foko Re, Ogo foko Re
Ogo f'oruko Oluwa

O tan aniyan elese
Ogo ni fun oruko Re
O fun alare ni simi
Ogo ni fun oruko Re

Ogo foko Re, Ogo foko Re
Ogo f'oruko Oluwa
Ogo foko Re Ogo foko Re
Ogo f'oruko Oluwa

Nje un o rohin na felese
Ogo ni fun Oruko Re
Pe mo ti ri Olugbala
Ogo ni fun Oruko Re

Ogo foko Re, Ogo foko Re
Ogo foruko Oluwa
Ogo foko Re, Ogo foko Re
Ogo f'oruko Oluwa
Amin



Credits
Writer(s): Awoyomi Oluwabukunmi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link