Ogo ni fun Oluwa

Ogo ni f'Oluwa to se ohun nla
Ife lo mu k'O fun wa ni OmO Re
Enit'O f'emi Re lele f'ese wa
To si silekun iye sile fun wa

Yin Oluwa, Yin Oluwa
F'iyin fun Oluwa
Yin Oluwa, Yin Oluwa
E yo niwaju Re
Ka to Baba wa lo l'Oruko Jesu
Je k'a jo f'ogo fun Onise-yanu

Irapada kikun ti eje Re ra
F'enikeni t'o gba ileri Re gbo
Enit'o buruju b'o ba le gbagbo
Lojukanna y'o ri idariji gba

Yin Oluwa, Yin Oluwa
F'iyin fun Oluwa
Yin Oluwa, Yin Oluwa
E yo niwaju Re
Ka to Baba wa lo l'Oruko Jesu
Je k'a jo f'ogo fun Onise-yanu

Os'ohun nla fun wa, O da wa l'ola
Ayo wa di kikun ninu Omo Re
Ogo ati ewa irapada yi
Y'o ya wa lenu 'gbat' a ba ri Jesu

Yin Oluwa, Yin Oluwa
F'iyin fun Oluwa
Yin Oluwa, Yin Oluwa
E yo niwaju Re
Ka to Baba wa lo l'Oruko Jesu
Je k'a jo f'ogo fun Onise-yanu
Amin



Credits
Writer(s): Awoyomi Oluwabukunmi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link