Ibere

Me I gat many many questions
Ti yoruba mọ si ibere
Kilo mu woli to n Ṣẹ epe
Ope ti o fẹ seke
Sẹ igbagbọ ni o kere
Abi o lewe to gboju le
Aye lamọ tan ti n we we
Ṣe Lọrun Ṣe wọn we ewe

Me I gat many many questions
Ti yoruba mọ si ibere
Kilo mu woli to n Ṣẹ epe
Ope ti o fẹ seke
Sẹ igbagbọ ni o kere
Abi o lewe to gboju le
Aye lamọ tan ti n we we
Ṣe Lọrun Ṣe wọn we ewe

Been on the road, for a very long time
Jẹ ka ya mi maja, ṣe ko ni Ṣẹlẹ
Ẹlẹda nijọ wo na lo ma Ṣẹlẹ
So I gatz Switch it up Ma Flow
Aṣakẹ na ṣi ni mẹẹdo
Owo olowo ṣe dun na
Ki lo mu ẹ to n ṣe ṣina
Ibere ti o ni answer
Kin ma bere rhetorical questions
Wake up Bake up
Kilo ma n Ṣe
Toba ti ji laro kutu
Gbagbe Ana, Ogo ni foluwa
To jẹ kin tun rọjọ Tuntun
Ọpọ lajọ sun tiwọn jimọ
Iwọ na mọ pe kin ṣe mofi yọ wọn
Ore ọfẹ ni kosi boṣe pọto
Koma le fa ni Lapo ya
Wọtun kowosi Awa ta wa nibi
Ṣa jọ eni toma gbeja wa
Tio ba ti jọrọ owo
Ọmọ Aunty mi we le ri signal wa
Latetekọṣe bẹ lo Ṣe ma wa yeah tititi ayeraye
Kosowo loọwọ mi mo Ṣin hustle ma ma pemi lalaye
Ọrọ ti mo n sọ mi o mọ boya o Correct
Kẹ ye ma Farawe
Buh taba n tulẹ, lẹyọ kankan
Ọmọ aunty mi ma ṣalaye
Nkan to ma kọ lolowo
Talika Na lo ti ni gba
Womi kotun mi wo
Toke tilẹ eeehh young farmer lo Ta
Abi kinma tu lẹ funwọn lẹyọkan kan
Wọn ni kinma Worry
Kin lọ oju Ọjọ Gan gan
Tinba ti de oju Ọja kini kinṣe gan gan
Iwọ ma Care ṣa ti bere ijaya Gangan
Ọmọ Aunty mi wa Lẹsọ Lẹsọ
Bo ṣe n ju ibadi yi ọmọ yi ẹru yi pọ
Bo ṣe n ju ibadi yi ọmọ yi ẹru yi pọ

Me I gat many many questions
Ti yoruba mọ si ibere
Kilo mu woli to n Ṣẹ epe
Ope ti o fẹ seke
Sẹ igbagbọ ni o kere
Abi o lewe to gboju le
Aye lamọ tan ti n we we
Ṣe Lọrun Ṣe wọn we ewe

Me I gat many many questions
Ti yoruba mọ si ibere
Kilo mu woli to n Ṣẹ epe
Ope ti o fẹ seke
Sẹ igbagbọ ni o kere
Abi o lewe to gboju le
Aye lamọ tan ti n we we
Ṣe Lọrun Ṣe wọn we ewe

Fun mi ni cash
Ko si Cash
Fun mi ni Cash
Ko si Cash
Fun mi ni Cash
Ko si Cash
Fun mi ni cash
Ko si Cash
Fun mi ni Cash
Ko si Cash
Fun mi ni Cash
Ko si Cash



Credits
Writer(s): Adeyemi Olofintuyi
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link