Kasimawo Session (feat. Samba.k)

Ẹ sọ fun gbọmọ gbọmọ koma binu lọja tan ba jọmọ ẹ gbe
E sọ fun abanijẹ koma binu lọjọ tan ba ti ba ti ẹ jẹ
Tori gba muri ni gbafun gbada
Owo jẹbu gan wọn Dapada
O le ṣe ti ẹ kin ma Ṣe temi Pada
Awọn to Giran bayẹn o pe Mẹwa
So tan ba ti fun ẹ ko ma jẹ
If u don't get it then forget it
Ti o ba ti ye ẹ ko gbagbe ẹ
Awọn elehi load irin biti Cartel
Ẹro pẹsẹ pẹsẹ n ti gbin
Ojo to rọ sewuro lo rọ sireke
Kin sọra mi di ọmọ bankẹ
Gogogo ti ge so mi o le ke
Pekelepekele arugbo jẹ gbese talo ma san
Ijọba ma San abofẹ san sanwo ma san
Ọmọge yọdi ẹ sẹyin Ara fẹ san
Owo oṣelu ni men ko ni le tan
Ọpa mose reeee ko ni kan
Ọrun n yabọ ni e ṣọrọ eyan kan
Ṣebi awo ni gbawo ni gbọwọ
Tawo o gbawo, awo bẹ afọ
Toba dẹ ti fọ ọgbẹri amu lọwọ
Nkan to ni lọwọ lo le ma manipulate
Gbogbo OGUN kọ ni ma ti participate
So a ma better kẹ corporate
Kale ri nkan ta ma Gboju le
Awo mo ṣe awo temi o tu le
Apala kọ hip hop re

Tested and trusted
Lyrics mi bad gan tẹ ti lẹ ko ma gbọ sẹ
Huh, Mo Ko ẹ jẹ hundred
Anybody wey look down on me ko ni bọ n bẹ
Yes, Make I yarn u you wan join league
Make i bam you wo, Fuck shit biti Man Utd
Ọmọ to set ọmọ lẹpa mo fẹ handle
Young rich Nigga Shatta Bandle
Conquer anything Mo ti tan candle
To ba ya ako lolo ma pe Uncle
O da yan mọ oya chop knuckle
Wọn da mọ O clear biti Netflix
Clear transaction yatọ si pending
Jẹ ko ma lọ on a low, No Rushing
Kala le pull up together Ninu Bentley
O ṣa mọ one two three o ni ending
Buju banty yatọ si Buju Bnxn
Huh! Romeo craig gbogbo Spending
Do am anyhow kowo yẹn ṣa ti plenty
Ko yapa ko plenty ko rọ pọpọ
Kin ma la, Kin ma ko jẹ ṣọkọyọkọtọ
Ko ma gbọn ko ma gbọn biti Bumbum
Kin la ẹ biti tom tom
From now till Kingdom come



Credits
Writer(s): Samuel Bakare
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link