Ire

Ìrè ówó pẹlu àlàfíà wá sí ọdọ mí
Kò wá sí ọdọ mí
Àtàndá orí mí ló mọ
As i no get today tomorrow go set
Ìrè ówó pẹlu àlàfíà wá sí ọdọ mí
(Kò wá o) kò wá sí ọdọ mí (kò wá o)
Àtàndá orí mí ló mọ
As i no get today tomorrow go set

I wan free myself
Don't bother me orí ìrè òfè èrò so i run from frenemies
Temptation on my shoulder every malam with his jug
Émi gán o kéré if i buy muscle kò pọ
Ah if e no soft all them bitches no go stay
Wọn à fí ẹsẹ fẹ nobody really care
Am awake i wan try again shey atọna mí kí èmi rí ọna lọ
Anytime i look in the mirror i see myself getting older
Life is short like abèlà no pain no gain ayè wà dá
Buckle belt double hustle orí ló mọ no be power
Living life with no regret má bawọn ló ìgbà yí pè má bawọn ní ego

Ìrè ówó pẹlu àlàfíà wá sí ọdọ mí
Kò wá sí ọdọ mí
Àtàndá orí mí ló mọ
As i no get today tomorrow go set
Ìrè ówó pẹlu àlàfíà wá sí ọdọ mí
(Kò wá o) kò wá sí ọdọ mí (kò wá o)
Àtàndá orí mí ló mọ
As i no get today tomorrow go set

Jamokrane! kò dùn kò pọ kò pé lémi n tọrọ
Bí mó ṣe nlù kò má dún o jọ má jé kín tọrọ (má jẹ kín tọrọ)
Kín tó lè jẹ èyán jọ má jé n jẹ èyán (ey ye é é)
Baba tọ mí sí ònà jọ má jẹ' kí n ṣina (ey e)
As i dey



Credits
Writer(s): Akeem Toheeb, Akeem Toheeb Agboola
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link