Getilo

Wọn ma ti geti mi lọ o
Mi o ni fesi
Wọn ma ti geti mi lọ o
Mi o ni fesi
All the evil them-a planning
All the backbitting thema doing
Ẹni d'eeru l'eeru tọ

Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Ay, epe a pelepe

See remedy, see genesis
See consequences of your calamity
Making money, loyalty
No be the same thing, bọda, roun si
O yọ'bọn l'Akoka
Lẹyin yẹn lo mọ pe ko proper
Oke lo n gbe oke, oke lo n gbe, eh ire
Ilẹ l'ọn gbe ọfọ, wọn maa ṣọfọ titi dalẹ o

Ẹni ika a ku sile, a jẹya titi dalẹ o
Ire lo n gbe oke, ire oke lo n gbe ire
Ire lo n gbe oke, lo n gbe oke, lo n gbe ire
How come I'm seeing so-so proper
Ẹ lọ bẹẹ wo lọwọ baba o
How come I'm seeing so proper
Ẹ lọ bẹẹ wo lọwọ baba o

Wọn ma ti geti mi lọ o
Mi o ni fesi
Wọn ma ti geti mi lọ o
Mi o ni fesi
All the evil them-a planning
All the backbitting thema doing
Ẹni d'eeru l'eeru tọ

Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Ay, epe a pelepe

Ṣe wọn l'ọn sọrọ rẹ? Dakun, ma ba wọn ja
Ṣe wọn l'ọn pẹgan rẹ? Dakun, ma ba wọn ja
Ikọọkan, ikọọkan lọmọ ọwọ yọ
Ikọọkan
Dakun, ma ba wọn ja, dakun, ma ba wọn gba
Ikọọkan, ikọọkan, ikọọkan, ikọọkan lọmọ ọwọ yọ
Ẹni ba ni ki o ku a ṣíwáju ẹ ku o
Ẹni to ni ko sun ko ma ji, a wẹwu ẹjẹ
Ma ki mi, ma pe mi si
Awọn t'ọn pẹgan, t'ọn ba fun ẹ ko mọ-ọnkọ

Fi gbigbọ ṣalaigbọ
T'ọn ba fun ẹ ko mọ-ọnkọ
Ah, fi gbigbọ ṣalaigbọ
Ma pe mi si, ma fe si
Geti mi lọ, wọn ma ti geti mi lọ
Ma pe mi si, ma fe si
Geti mi lọ, wọn ma ti geti mi lọ

Wọn ma ti geti mi lọ o
Mi o ni fesi
Wọn ma ti geti mi lọ o
Mi o ni fesi
All the evil them-a planning
All the backbitting them-a doing
Ẹni d'eeru l'eeru tọ

Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Epe a pelepe to ba ya o
Ay, epe a pelepe

(It's Bizzle on the mix)



Credits
Writer(s): Alexander Abolore Adegbola Akande
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link