Gbajumo
(Music)
Say it again
And say it again
A o ṣ'oro, a o ṣ'oro (a o ṣ'oro, a o ṣ'oro)
Ikoko aje to kun f'omi
Ma ri bu, ma wẹ
Ko mu ire ko wa o (won't you say it for me, for me o?)
Ti ire ba de, ma rẹrin ayọ (won't you say it for me, for me o?)
Tori mo ko're lọna
Ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti
Ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti
Ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ, o ya, ṣe ẹẹkan si o
Kaka ki
Kaka ki gbajumọ mi j'ọpọlọ o
Ẹni maa gba kọnkọ fun a jade
Ọṣunrin lo gbayi ju ninu igi
Ọkin lo gbayi ju ninu ẹyẹ
Ogbomu lo gbayi ju ninu ewe
Ọba lo gbayi ju ninu eeyan
Kaka ki
Ki n ma gbayi nile, loko
Ọmọ ẹru a jọba, ile a fojuro
Baba, baba, baba
I go dey busy spending money
Making money pieces
I go dey busy spending money
Make money like pieces (pieces)
A o ṣ'oro, a o ṣ'oro (say it again)
Ikoko aje to kun f'omi
Ma ri bu, ma wẹ
Ko mu ire ko wa o (won't you say it for me, for me o?)
Ti ire ba de, ma rẹrin ayọ (won't you say it for me, for me o?)
Tori mo ko're lọna
Ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti
Ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti
Ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ, o ya, ṣe ẹẹkan si o
Ṣ'owo ni? Ṣ'owo?
Ṣ'owo ni? Ṣ'owo?
Money na paper, fi ran mi
(It's Bizzle on the mix)
O pọ, ṣ'owo ni? Ṣ'owo?
Ṣ'owo ni? Ṣ'owo?
Money na paper, fi ran mi
Say it again
And say it again
A o ṣ'oro, a o ṣ'oro (a o ṣ'oro, a o ṣ'oro)
Ikoko aje to kun f'omi
Ma ri bu, ma wẹ
Ko mu ire ko wa o (won't you say it for me, for me o?)
Ti ire ba de, ma rẹrin ayọ (won't you say it for me, for me o?)
Tori mo ko're lọna
Ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti
Ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti
Ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ, o ya, ṣe ẹẹkan si o
Kaka ki
Kaka ki gbajumọ mi j'ọpọlọ o
Ẹni maa gba kọnkọ fun a jade
Ọṣunrin lo gbayi ju ninu igi
Ọkin lo gbayi ju ninu ẹyẹ
Ogbomu lo gbayi ju ninu ewe
Ọba lo gbayi ju ninu eeyan
Kaka ki
Ki n ma gbayi nile, loko
Ọmọ ẹru a jọba, ile a fojuro
Baba, baba, baba
I go dey busy spending money
Making money pieces
I go dey busy spending money
Make money like pieces (pieces)
A o ṣ'oro, a o ṣ'oro (say it again)
Ikoko aje to kun f'omi
Ma ri bu, ma wẹ
Ko mu ire ko wa o (won't you say it for me, for me o?)
Ti ire ba de, ma rẹrin ayọ (won't you say it for me, for me o?)
Tori mo ko're lọna
Ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti
Ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti
Ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ ki i ṣe nnkan ti
Gbajumọ, o ya, ṣe ẹẹkan si o
Ṣ'owo ni? Ṣ'owo?
Ṣ'owo ni? Ṣ'owo?
Money na paper, fi ran mi
(It's Bizzle on the mix)
O pọ, ṣ'owo ni? Ṣ'owo?
Ṣ'owo ni? Ṣ'owo?
Money na paper, fi ran mi
Credits
Writer(s): Alexander Abolore Adegbola Akande
Lyrics powered by www.musixmatch.com
Link
Other Album Tracks
© 2025 All rights reserved. Rockol.com S.r.l. Website image policy
Rockol
- Rockol only uses images and photos made available for promotional purposes (“for press use”) by record companies, artist managements and p.r. agencies.
- Said images are used to exert a right to report and a finality of the criticism, in a degraded mode compliant to copyright laws, and exclusively inclosed in our own informative content.
- Only non-exclusive images addressed to newspaper use and, in general, copyright-free are accepted.
- Live photos are published when licensed by photographers whose copyright is quoted.
- Rockol is available to pay the right holder a fair fee should a published image’s author be unknown at the time of publishing.
Feedback
Please immediately report the presence of images possibly not compliant with the above cases so as to quickly verify an improper use: where confirmed, we would immediately proceed to their removal.