E Ma Ro'pe

Ema ro pe ko le lowo mo
Eni to jegun si ma je ran
Ore ma ro mi pin eni to wakisa si le woso
Igba yi to le o nbo wa dero
Afaila ojo bojo ba la ma la

Ema ro pe ko le lowo mo
Eni to jegun si ma je ran
Ore ma ro mi pin eni to wakisa si le woso
Igba yi to le o nbo wa dero
Afaila ojo bojo ba la ma la

Eniyan mi wonu Olorun mi wokan o
Oni ero mi ki nse ero yin rara
Eda o laropin
Eni ta ro pe koke pago le sebe ko kole alaruru
Oju lo pe si isoro oni o a la dun ola o
O somo oloku be a ko si se mo
Afaila ojo bojo ba la ma la

Ema ro pe ko le lowo mo
Eni to jegun si ma je ran
Ore ma ro mi pin eni to wakisa si le woso
Igba yi to le o nbo wa dero
Afaila ojo bojo ba la ma la

Wipe mo nwa ki sa lo ni ko tun mo pe mi o logo kan rara
Wipe o nje mi o leran ko ni nwo nile la lu yo
Owuro aye mi o le ma tun mo osan
O san aye ti mo wa o le ma sapejuwe ale
Ohun ti mo mo daju ni pe
Bo pe bo ya akololo mi a pe baba
Be lo se Abrahamu baba igbagbo pata

O doju ko Esteri o pada o wa d'ayaba
Isoro koju Danieli la teru de iho kinihun
Be ni Josefu pada joba ni soju gbogbo ota
A te ni fe mi fe re a te ni fe mi fe bi
Oro mi a da ri yan ji yan loju eniyan gbogbo
Jesu a ba mi jo yin lo ju

Ema ro pe ko le lowo
Eni to jegun si ma je ran
Ore ma ro mi pin eni to wakisa si le woso
Igba yi to le o nbo wa dero
Afaila ojo bojo ba la ma la

Oju ojo a la o mo shi ma jeran ni po egugun
Ke ni keni ma ro mi pin o ma dara fun mi
Aiye mi a layo mi o ni sha ko ba ta fegbe
Emi a ri re loju aye mi
Ero Lorun si te mi ni

Ema ro pe ko le lowo mo
Eni to jegun si ma je ran
Ore ma ro mi pin eni to wakisa si le woso
Igba yi to le o nbo wa dero
Afaila ojo bojo ba la ma la

Ema ro pe ko le lowo mo
Eni to jegun si ma je ran
Ore ma ro mi pin eni to wakisa si le woso
Igba yi to le o nbo wa dero
Afaila ojo bojo ba la ma la

Ema ro pe ko le lowo mo
Eni to jegun si ma je ran
Ore ma ro mi pin eni to wakisa si le woso
Igba yi to le o nbo wa dero
Afaila ojo bojo ba la ma la



Credits
Writer(s): Bioku Llc
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link