Omo Tuntun

Omo tuntun omo tuntun omo dara
Omo tuntun omo tuntun ko soun to da bi re
Omo tuntun omo tuntun se bomolere aye
Omo tuntun omo tuntun omo dara
Omo tuntun omo tuntun ko soun to da bi re
Omo tuntun omo tuntun se bomolere aye
Mo ti fi gba kan ri je omo tuntun
Ko soun bi omo
Baba mi fi gba kan ri je omo tuntun
Ko soun bi omo
Yeye mi fi gba kan ri je omo tuntun
Ko soun bi omo
Omo lade ori omo laso omo nide
Ko soun bi omo
Gbogbo wa lati fi gba kan ri je omo tuntun
Ko soun be omo
Omo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Omo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Jesu Kristi fi gba kan ri je omo tuntun
Ko soun bi omo
Gbogbo aye foribale awon amoye metaa mu ebun wa
Ko soun bi omo
Omo niyun omo nide omo lade ori omo laso
Ko soun bi omo
Se bomo ni ini oluwa omo inu si ni ere re
Ko soun bi omo
Gege bi ofa se ri lowo alagbara be ni omo se ri
Ko soun bi omo
Jeje bi ofa se ri lowo alagbara be ni omo se ri
Ko soun bi omo
Omo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Omo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Mo ti fi gba kan ri je omo tuntun o
Ko soun bi omo
Gbogbo ara ile gbe mi jeje
Ko soun bi omo
Omo laso iyi omo lafe aye ori je bi temi
Ko soun bi omo
Ori je dagba kin tagba da komo rere gbeyin mi o
Ko soun bi omo
Edumare mo be o jowo je bi temi komo rogba yi mi ka
Ko soun bi omo
Omo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Omo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Mo gbadura fun awon agan ko fi nu soyun ko fi eyin gbomo pon
Ko soun bi omo
Bo ti gbadura ni Shiloh ati serah gbo adura won baba o
Ko soun bi omo
Bo ti gba ti Elizabeth jowo ranti won si rere o
Ko soun bi omo
Ebu ofe to sokale wa lomo re leyin wa to agba wa dagbalagba
Ko soun bi omo
Omo tabi leni a dagba a dogbo a dolorire lori ile yi o
Ko soun bi omo
Omo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Omo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Ori mi jowo fun mi ni temi je room peranise o
Ko soun bi omo
Eni a raso loja ola ara so loja aso a segbe to ba ya omo n kara
Ko soun bi omo
Emi a jeun ku fun omo mi omo laso
Ko soun bi omo
Adagba jeun ku fun eyele awoko ejun ku fun adaba omo re a gbeyin mi
Ko soun bi omo
Omo lasede aye ori je bi temi
Ko soun bi omo
Omo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Omo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Omo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Mo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Omo tuntun omo tuntun alejo aye ku abo
Ko soun bi omo
Omo omo o lere aye ko soun to da bi omo
Ko soun bi omo



Credits
Writer(s): Sola Allyson, Tolu Fafowora
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link