Ololufe Mi

Ololufemi, ti e ni mo fe
Alayanfemi, ti e ni mo fe
Ololufemi
mi o se ti won mo
Alayanfemi, ti e ni mo fe
Wa fenu ko mi lenu oooohooo
Wa fara ro mi lara o

Hey hey hey hey hey

Alayanfemi, ti e ni mo fe
Ololufemi, ti e ni mo fe
Alayanfemi
mi o se ti won mo
Alayanfemi, ti e ni mo fe
Wa fenu ko mi lenu
Wa fara ro mi lara o



Credits
Writer(s): Fela Anikulapo Kuti
Lyrics powered by www.musixmatch.com

Link